Adamallahu Ayatahu Yah Sheik Buhari ibn Musa (Ajikobi 1) Al-adaby al-ilory Olohun ba wa se alekun Ike, ige ati aforijin fun Baba Agba Sheik Ahmad Nda Salaty al-ilory ati gbogbo awon Omo won, Omo Omo ati gbogbo Muridi/Muridah ati gbogbo awon Alfa wa/Obi wa ni ilu Ilorin ti won ti lo pelu gbogbo oku Islam Ile Sheik Nda Salaty koni baje lae-lae ati ilu Ilorin lapapo Aamin Thuma Aamin