ExcelTv Is a new promising RU-vid entertainment channel with a difference. It's a channel built that offers you worthwhile viewing pleasure and experience of Yoruba music video entertainment and it's like. It showcases Yoruba heritage and culture to entertain, educate and captivate the viewers through it's premium Nollywood Yoruba movies showing for Free. ExcelTv is Powered by Excel Films And Records International.
Follow us on Facebook: web.facebook.com/ExcelTvchannel/, and web.facebook.com/Excel-Films-Production-169308807028446/
Follow us on Instagram: @ExcelTv, and @Excel_Films_Production
........ExcelTv!!! THE LANGUAGE OF QUALITY........
Baba se bi e se soro ni aiye Jonathan niyi????E je ki a bi arawa leere....Pelu epe ni e fi sin Jonathan jade kuro lori ipo nitoriwipe ilu le nigba na bi o ti le jewipe ko ti e le to eleyi .....Ati ijoba ti ijarun ati ti ijeta ati ti oni, ewo ni ko kopa ninu ara won.....Se Tinubu ko si lara won ni? Se Tinubu se bere oselu lana ni?..... Baba is high time we should stop given excuses for all these policuans....Baba n je 90billions ti Tinubu ko sile fun Hajj ba ojumu? Ti ebi si n lu awon eniyan pa....N je baba e ti gbo wipe Tinubu yi ra presidential jet ti owo re n lo bo 150million dollar? Baba o ye ki e soro nipa eleyi na....Abi bawo ni inaki se sori ti obo o se? A fe gbo yi ki e bawa soro gba Tinubu lori pelu gbogbo radarada ti o n se.....Baba a n reti o
Honestly l am not a Muslim but this is not religion but honest truth. Grandpa. Greater Anointing, more wisdom, more strength. Long life. God will minister to them to listen and do what our cleric is saying. Hmmm.