Тёмный
Joyce Meyer Ministries Yoruba
Joyce Meyer Ministries Yoruba
Joyce Meyer Ministries Yoruba
Подписаться
Kaabo si Yoruba RU-vid Channel ti ijo Joyce Meyer. Joyce Meyer jẹ ọkan ninu awọn olukọni Bibeli ti o wulo ti o si tayo ni agbaye. Awọn iwe rẹ ti ran ọpọlọpọ awọn eniyan lọwọ lati ri ireti ati atunṣe nipasẹ Jesu Kristi. O tun je olootu eto kan lori TV ati redio, Jije Igbadun igbesi-aye Ojojumo ®, eyiti owa lori afefe kaakiri agbaye

Ife Joyce lati ṣe iranlọwọ fun awọn eniyan ni ojoojumọ ni iran si iranwo fun ireti, apa iṣẹ ti ijo Joyce Meyer. Anowo si wa kaakiri agbaye ni awọn eto ṣiṣeunjẹ, itumọ awọn kanga omi, awọn itọju ilera, awọn ile fun awọn alainibaba ati awọn eto ti o koju ijapa ọja eniyan.

Ti o ba ni ibeere eyikeyi nipa ijọ Joyce Meyer Yoruba, jọwọ kan si wa lori yoruba@jmmwo.org / +234 809 22 22 11 7.
Yan Igboya Dipo Ẹru   4-1 | Joyce Meyer
25:43
19 часов назад
Gbigbe Laisi Ibanujẹ  1-1 | Joyce Meyer
26:02
3 месяца назад
Idajọ ati Ilodisi  1-2 | Joyce Meyer
23:01
4 месяца назад
Rinrin Ninu Ifẹ  3-2 | Joyce Meyer
25:14
4 месяца назад
Rinrin Ninu Ifẹ  3-1 | Joyce Meyer
25:37
4 месяца назад
Itan Ọmọ-Ọdọ Alainidariji | Joyce Meyer
25:44
6 месяцев назад
Bi Igbagbọ Se n Sisẹ | Joyce Meyer
26:44
7 месяцев назад
Bi Igbagbọ Se n Sisẹ | Joyce Meyer 1278 2
25:58
7 месяцев назад
Enu 3-2 | Joyce Meyer Ministries Yoruba 1275 2
25:47
8 месяцев назад
Enu 3-1 | Joyce Meyer
26:34
8 месяцев назад
Комментарии