I Thank Jesus that i can find full of this sermon I watched the short one on TikTok and ever since then have been searching for the full ministration and I'm So Blessed finding it. I received POWER 🔥🔥🔥🙏
Ẹjọ́wo ẹ bá wà gbé àwọn program màmá Erelu àgbáyé to tí wá di Erelu Jésù báyìí, àsìkò yí gàn tí ojú gbogbo àwọn ẹ̀yán tí la, ní ọ̀rọ̀ màmá Erelu le wo etí àwọn onigbagbọ gidi., kí Ọlọ́run wa pẹlu màmá Erelu. Àmín