ORIYOMI HAMZAT SECRET LEAKED | ÀṢÍRÍ ORIYOMI HAMZAT NA TÍ TU O, BÓ ṢE SẸLẸ SI AGBALA GABRIEL ÀTI MUYIDEEN Please subscribe, like, comment and share #viralvideo
Thank you BROTHER GOD BLESS YOU , GBOGBO AWON TO NSE ADE KOYA FUN MUYIDEEN WON MAA JIYA LAGBARA OLOHUN, ISE OLUWA KO YE AWON OPONU, OLOHUN FERAN MUYIDEEN NI O JEKI O SE ALABAPADE GABRIEL ATI IYAWO TI MUYIDEEN FE, LATI YI IGBESI AYE RE PADA SI RERE PELU ADURA .ATI AAWE TI O GBONA GIRIGIRI , EBE SI OLOHUN TI O SE ISEDA MUYIDEEN. AWON WERE ABIYAMO TI SO PE JEJE NI MUYIDEEN NTA OJA RE JEJE LORI TITI TI AGBALA LO KO WAHALA BA MUYIDEEN, IMAGINE, EMI.KAN NWO AWON BLOGGERS ATI AWON ALFA YEN PE ORI WON KO PE RARA, AWON NI WON NKO MUYIDEEN NI IRO BURUKU TI O NPA MO GABRIEL. WON TI GBAGBE PE OLOHUN LO GBE GABRIEL DIDE FUN AWON TI AYE WON TI BAJE BI MUYIDEEN. AWON ONILARA OSI, ETI WON TI DI SI ORO OLODODO, IDI IBAJE ATI ABOSI GABRIEL NI WON MAA KU SI LAGBARA OLOHUN. ESE SI EMIMIMO KO NI AFORIJI NIWAJU OLOHUN GBOGBO AWON OTA GABRIEL TI SE OLOHUN, WON TI FENU KO.
Oriyomi is equally a hypocrite. The day he said, koni daa fun yin ateni ten gbeja. That was the day I knew he's bereaved of intellectual property. The truth will invariably triumph no matter how juicy the lie is.
SE ORIYOMI HAMZAT TI GBAGBE STORY YI NI, O MASE OOO, YORUBA KO FERAN ARA WON RARA, A FI KI OLOHUN GBA WA OO. OLOFO NI GBOGBO AWON OTA GABRIEL OLOGO OMO, AYANFE OLODUMARE,
This is a disgrace to Oriyomi.u should be ashamed of yourself,so you have done worse things than Agbala and you followed Muyedeen to A G as if you are innocent this is terrible why are you so jealous of this man you are older than him,you have been known throughout the world,you are making it still you are not satisfied why,why,n why God will judge you.Everybody looking or seeking for A G down fall God Almighty will make the entire family members of those people to fall down flat IJN
Itara ki işę owo Gabriel ma baję loşe na Muyideen, boya koni ta tętę mo, ki aiye ę le dara. Olotito koni ku sipo ika. Muyideen ko mope won ti le anu kuro lara owun. More grace sir.
Egun idile baba Muidini ni ko pada lehin re lgbala okan re ni Olorun fe gbogbo ohun ti on ri loni ile ni owo ni kosi ohun ti yio mu lo Emin re nikan ni yio pada to Olorun lo yio jabo ise iriju re gbogbo wa ko le se alai ma fara han niwaju ite idajo ki olukuluku ki ole gba ere ise ti ose ninu ara iba se rere iba se buburu
Awon bloggers olori buruku gbogbo, oro ti ko soju won ni won nse eeri re bi enipe won.wanibe. OLOHUN MAASE IDAJO INA FUN GBOGBO WON ENITI OLOHUN BA TI DA KO SEE FI ARA WE, WON KO RO OJO ALE WON, TI YIO KORO JU EWURO LO. LOLA ANABI ONISE NLA.
@@DAAEXPRESSIONTV essir sheriwipe esin Christian.ti di esin eru because awon pastor yen ma nlo si.odo awon babalawo nitori eh ni awon Omo ijo naa ma n support iwa ika ti pastor ba Wu ti EMI baje Christian ojo ti pastor ba na eniyan ni church Mio tun yabemo iyen pastor tiko popular ooo ....Agbala Gabriel kotie fit eni to le na eyan Mio rowipe o le strong face eh sef
This is a disgrace to Oriyomi.u should be ashamed of yourself,so you have done worse things than Agbala and you followed Muyedeen to A G as if you are innocent this is terrible why are you so jealous of this man you are older than him,you have been known throughout the world,you are making it still you are not satisfied why,why,n why God will judge you.Everybody looking or seeking for A G down fall God Almighty will make the entire family members of those people to fall down flat IJN