Marriage ti won fi ngba eru lori okunrin ni millions of women ti eri okan won ti ku patapata nse laiye ti a wa bayi. Oto ni okunrin ti won koko fe ti won fi atalanta baba iya je won ti o wa je wipe okunrin ti won ba ni ki o fi oruka bo won lowo ni won maa lo ya oro lara re.