Esi iwe ti Yoruba nation ko si president ni a nfe. Ki ise ipade apapo Yoruba. Ti won ba fesi iwe ti Yoruba nation ko si president ti Nigeria, ni won to le pe ipade apapo. Bibeko ipade na lewu. E jeki a ronu jinle ki a to ma se ipade apapo. Eyin ojogbon Yoruba nation, e fi ogbon seo. Ojo ti pe ti Yoruba nation ti nse apero. Ko si eniti o mu imoran iru ipade yi wa. Ifura logun agba o. Eyin ojogbon Yoruba nation. Olohun Oba yio segun awon olote Yoruba nation o. Amin ati Amin.
Eku ise ani ani ko si ifokanbale lafe NO GOING BACK YORUBA NATION YORUBA NATION YORUBA NATION Olorun to dawa si ile YORUBA NATION yio tiwa leyin thanks
Chief Dr. Sunday Adeyemo Igboho kogbodo lo si ipinle Lagos rara fun ipade lobaloba ti Tinubu pe si odo Young oba elegushi. Kinide ti won osese meeting yen ni odo Oni of Ife oba Oguwusi ti oje oba Yoruba land E jowo e sofun chief koma wa si Nigeria lowolowo yi. Olewu o Again awa omo Yoruba akofe Regional Government rara rara won fe fi tanwa pada si okoeru ni.o. sebi ati se tele ko gbewa rara nigbayen sebi oun ni asewa ni oko eru disinyi. Meeting iro ni won fe se, e ma da won lohun at all. Yoruba Nation lafe, Yoruba Nation mikan ni solution si oro to wa nileyi. Yoruba Nation no going back.
Sunday igboho must not come to Nigeria this time of their so called meeting they’re trying to arrest him, may God bless Yoruba land Yoruba Nation la fe ni bayi bayi.
No way for the regional government in YORUBA, all we need is what God Almighty has given us from the creation of the world. YORUBA NATION no going back.