Oluwo is very comical, and innovative. He knows how to provoke his haters! He is RIGHT about our forefather Adam - the first man that God created! He has the DNA of Adam in him, that is why he wants to serve the God of our forefather 😁 I love this chap!
@@onlinework4521 Gẹ́gẹ́ bí àwọn ìran rẹ ṣe wà láti England. Ṣèbí èdè Gẹ̀ẹ́sì ní àwọn baba-nla yín má ń sọ? Aláìmọkan! Mo ṣàlàyé oun tí kò yèé fún ni. Ìwọ tí kò yé ń dá síi. Lọ̀ọ́ sinmi sílé jàre. Òún pè èèyàn l'afọ́jú. Kí ní ẹrí kàn pé Ọ̀rúnmìlà and Ṣàngó bọ̀ òrìṣà rí nígbèsíayé wọn?