Haaa!!! Aiye ma ni ka ooooo!!! Where are the families when suebebe was seriously down? Ore ma ni wanooo The God of Agbala Gabriel will caused anyone that plan evil against him
Kunle ologun dudu eleda pastor Gabriel Ademola Amusan ma gbe ogun dide sie tomotomo adabi ti kin ba se oore ni Agbala Gabriel se fun Dayo Adewumi Suebebe nikan loku..kunle ologun dudu how much is your donation to Dayo Adewumi Suebebe if not kunle ologun dudu iku esin loma ku danu ni agbara olorun amin ase Edumare...adabi tio ba da owo fun agbala Gabriel ninu ile Suebebe nikan loku...
Oloriburuku ni ologundudu. Alfa ,e seun. Awon omo Suebebe ti sope awon o ran ologundudu n'ise kankan o. Won ni awon o mo si o. Igbati won contact ologundudu, o ni oun ko mo eniti o ran oun n'ise. O ni won phone oun ni. Awon ajiginni ati folorunsho ati lekan ni won wa nidi oro yii. Gbogbo won a l'ule ni l'agbara Olorun. Amin.
Baba Ologundudu has to come out publicly to apologize to Baba Suebebe children and Agbala Gabriel for defamation of character, and bring down the video.
All these people are crazy and ingrate. Alfa you said it all. Ologundudu shouldn’t involve himself in this. Agbala Gabriel is doing his charity to the needy and I don’t know why all these nonsense.
What exactly do these people want from this young Pastor?Let him breathe,God is gracious and plentiful in mercy No matter how much sin a man committs Jesus Christ accomplished salvation work and His Blood is sufficient to wash away our sins.Stop condemning Pastor Ademola for Jesus Christ is his Advocate and Redeemer by His Blood.Everyone should be watchful and stopping fighting God.Pslm2
Ologundudu ti ya were patapata. Ologududu should be sue for defamation of characters. Agbala Gabriel should sue Ologududu for Ten Billion Naira for defamation of character.
Gbogbo eyin oloriburuku ota pastor Gabriel Ademola Amusan of agbala Gabriel emi mimo yio gba ifokanbale yin ni oruko Jesu amin adabi ti o ba je wipe oore lo se fun Muyideen ati Dayo Adewumi Suebebe nikan loku...
Kunle ologun dudu bio se npariwo agbala Gabriel yi ikunle awon abiyamo mo pe awon omo re pa ni agbara olorun amin ase Edumare adabi tio ba je wipe oore ni Pastor Gabriel Ademola Amusan of agbala Gabriel se fun Dayo Adewumi Suebebe nikan loku....
Kunle ologun dudu ofo lomi efo nse ofo ni lwo ati awon tio gbe ise Agbala Gabriel fun e ma se danu ni agbara olorun amin. Adabi ti kin ba se oore ni Agbala Gabriel se fun Dayo Adewumi Suebebe nikan loku ase Edumare
E ranti o Sule sue bebe funra alara re lo ranse pe Ademola Amunsan pelu Ebenezer wipe ki o da si oun, a she wa so ore di ejo fun se ore se ore.toh Olorun a dawo abo le Ademola Amusan ko si ni fi sile fun wahala, e ku eto o.
Ologun dudu, oonijere, o maasofun ni iwo ati idile re. Olorun maa ba tiyin je ni. Won fise ran e oo si mo oruko ati phone no eni to ran e nise haa Olorun a da e lejo iwo agbaaya yi. E o de fi Agbala we omo inu yin, o ma se o. Kuku so wipe awon ebi Muideen lo ran e nise, gbogbo yin patapata le maa kan idin ninu iyo lagbara Olorun.
Ologundudu is a fool and a crass idiot. Suebebe confirmed that he requested that the house should be built inside Agbala Gabriel area. It costs a lot of money to take care of his medical treatment while alive. He was even buried beside the house. What else?
Agbala Gabriel koni subu lase edumare. Isubu Gabriel ni opolopo eyan nwa. Sugbon Eniti Olorun yan oun loyan. Eni ti oyan lose logo. Ologundudu kosi opolo fun yin mo.
Eniyan ika ati alaiinironu ni Kunle Ologundudu. Afiibisuoloore eniyan patapata ni Ologundudu. He's started thumbling and he will finally be put to shame and disrepute in Jesus Name.
Suebebe told Agbala he wanted to live around Agbala in Ibadan. Agbala paid for all medical bills as needed even burial costs including the housekeeper and caregivers. Ologundudu opo re ti dudu. The children appreciated what Agbala did. No one sends you any messages. You collaborated with Mutindeen Alfas and their followers.
E o tipoto ,gbogbo enyin agents of satan , Ori Omo Amusan will be troubling you , so all of you will come out to confess .Suebebe was buried by the side of his house , then which property are you helping them to cry for ?.