AYINLA OMOWURA..... OMO ODUN 19YEARS OLD NI MO WA NIGBATI MO DARAPO MO BAND AYINLA OMOWURA
.
ORIN TI AYINLA OMOWURA KO, TI O DARUKO AYINDE NINU RE.... KI N SE SIKIRU AYINDE BARRISTER LO N BAWII.... AWON FANS LO N DA WAHALA SILE NIGBAYEN
.
CHIEF SIKIRU OYEWOLE.... OKAN LARA AWON ELEGBE AYINLA OMOWURA
.
PLEASE SHARE #viral #viralreels #music #likeandshare #viralmusic #yorubahood #yorubaplay #ayinlaomowura #comments #view @KLFD29743
5 окт 2024