"Ibukun ni fun omoodo na ti o fi ogbon se"... E je ki a wa ore kun ore, ni iwa , ni oro, ni iwasu, ati ni ise, paapa pelu awon alagbara aiye. Ki Olorun awon Baba wa ko ran wa lowo, ko kowa mo se. Amin.
Yes, let Yoruba nation become a reality before the rapture. After the rapture, it will be hard. Kosi awon ti yio roju raye. Better now to have president Tinubu divide the nation now!