Тёмный

EEGUN JADE NIGBALẸ:YAHYA BELLO TI YỌJU SI EFCC 

Alaroye onlinetv
Подписаться 80 тыс.
Просмотров 9 тыс.
50% 1

Yahya Bello reports to EFCC office.

Опубликовано:

 

19 сен 2024

Поделиться:

Ссылка:

Скачать:

Готовим ссылку...

Добавить в:

Мой плейлист
Посмотреть позже
Комментарии : 33   
@aladjimoustaphaiguewassiou9576
Ọgá awọn olè ni Naijiria,TINUBU ti dà sí ọrọ yaya bello,oni ki awọn efcc jáwọ ninu ọrọ ẹ
@TIOLUWANIOPECAROLINE
@TIOLUWANIOPECAROLINE День назад
Efcc o le sope awon oo ri yayah bello
@moriamonifade3919
@moriamonifade3919 День назад
Haaaaa pelu gbogbo owo ipinle Kogi tii Yaya Belo koje eleda awon mekunnu adaa fun Yaya Belo koni fii ifokanbale noo gbogbo owo tokoje lagbara Olohun.
@kemoblunsky3794
@kemoblunsky3794 День назад
Kpai him, oleeee, barawo, eleribu ofo
@KadriHammed-iz9yr
@KadriHammed-iz9yr День назад
Iyawa alaroye Ogun yahaya bello ti mun eyin naa e lo gbo ohun ti e ka SI wa leti nigba ti Oro yen Koko sele sugbon bayii oti tutu Lara tiyin naa oga oooo
@abdulwahabahmad4983
@abdulwahabahmad4983 День назад
Iyato wa laarin igba ti Iya-Alaroye ba nka Iroyin, ati Igba ti oba nka Osoju-mi-Koro. Iroyin lasan ni won nka nibi, Kokii se wipe won nso ti ti inu won!.
@mariamasie9329
@mariamasie9329 День назад
Yaya Bello duro de awon iya ki won sope ko yoju koto yoju ni,mo gbedi fun APC
@adekunlefodilullahmfa7700
@adekunlefodilullahmfa7700 День назад
😂😂😂😂 Haaa o yaa ni leenu gan 😅😅😅 Erin si paa mi ni gbati mo gbo iroyi yii ooo Oro radarada ooo 😅😅😅 9ja EFCC alailoju tii
@olasunkanmiademola6309
@olasunkanmiademola6309 День назад
Took so long to prepare ground for eventual escape routes. Politicians are the only Nigerians that can do this
@Adugbo
@Adugbo День назад
Oye kiwon pa danu ni
@OlasunkanmiFasasi
@OlasunkanmiFasasi День назад
Nigbati ise pe si lara tan. Eniti ko mo bi egbe ti la onitoun a sare ku. Kare mo gba fun e.
@muritalaakande69
@muritalaakande69 День назад
Oro sunukun
@timothywale8055
@timothywale8055 День назад
Se Eleyi lo ngbogun ti ikowoje ,ati iwa obaje ? Odara o koburu o
@TracyKnight-uq7gm
@TracyKnight-uq7gm День назад
Hmmmm olorun wa
@josepholaniyan6468
@josepholaniyan6468 2 дня назад
At last
@AdekunleZainab-yt7tk
@AdekunleZainab-yt7tk День назад
Won ti duna dura tan humm 🤔 eyin nihun Olorun ni hum 😎
@muritalaakande69
@muritalaakande69 День назад
Eke nbeke soro, iro nparo funro.
@AwosikaFelixboro
@AwosikaFelixboro День назад
Ole ni gbogbo yin
@Ire...6838
@Ire...6838 День назад
Koni da fun gbogbo awon Oloriburuku eda nyin...
@alabaadejumo535
@alabaadejumo535 День назад
olee ngbẹ olee lẹhin, ẹ jọwọ mama alaroyè, ẹ ba wá sọ fùn won pe ilẹ yorubá ti kuro niun nigeria, ki awon olee gomina fi ipo ẹtọ ọmọ yorúbá silẹ fùn wa. ẹ ṣẹ gan.
@reusamanda9758
@reusamanda9758 День назад
You be mumu
@alabaadejumo535
@alabaadejumo535 День назад
@@reusamanda9758 ko ni pẹ́ ti a ma ri ẹní ti o jẹ muumu. slave master.
@reusamanda9758
@reusamanda9758 День назад
@@alabaadejumo535 ile Yoruba ti kuro ni Nigeria 😂😂😂how exactly ???
@alabaadejumo535
@alabaadejumo535 День назад
@@reusamanda9758 go to the google, ko lọ yẹ wo. iya alaroye on line, mọ ko ni sọ fùn ẹ ni.
@mariamasie9329
@mariamasie9329 День назад
APC ki se eran riro,eri ti won kun awon agbejoro Peter Obi lorun ninu kotu.
@ToyinOshagbemi
@ToyinOshagbemi День назад
Oro ni, nibo leti gbo?
@lukmonolamilekan8616
@lukmonolamilekan8616 День назад
Ilu yio ledaa mo akan tanrawa jee lasan ni
@OpadoyinJonathan
@OpadoyinJonathan День назад
Olorun yo se dajo
@olarinwaleafeez
@olarinwaleafeez День назад
Ni bololo lati ojoyi
@comfortadeoye5748
@comfortadeoye5748 День назад
E maa ta.ara yin je gbogbo yin
@ajokenimi1791
@ajokenimi1791 День назад
Hummmm.. mmmmmm
Далее
А вам, слабо?
00:22
Просмотров 30 тыс.
IBRAHIM CHATTA & YINKA AYEFELE FIGHT KAMO STATE
11:35
Просмотров 107 тыс.
Why has badminton become code for sex in Hong Kong?
12:46
Who is this Allah?
23:13
Просмотров 7 тыс.
I BEAT MY WIFE TO STOP HOOKUP || Justice Court EP 193
27:02
ODUNLADE & KAMO STATE  🤣🤣🤣
10:57
Просмотров 140 тыс.