They have their Emir there so they should go complain to their Emir. Oluwo didn't learn from Afonja, He actually thought they would be on his side for pushing and preaching Islam. He's gonna learn the hard way. The same man that opened his cap to honor another people's culture and traditions say people should be coming to Iwo to buy stuff now they're destroying one of the things being produced in Iwo. Nonsense king.
Awon omo ale jati jati,rede rede,raun raun,pala pala ilu apala. Awon enia buruku ,omo ale ti nfi owo osi juwe ile baba re ni Oluwo ati mufti omo igbira akkotileta yi je.
Since the Kabiyesi is the sponsor of Herdsmen in Iwo, he should be sent the bill for the damage. Oluwo and his 'agenda' will be exiled to Ilorin laslas ni! 😂
@@arinolamayaki7487 Awọn màdàrú to wa ni Ilorin ni wọn fẹ ki gbogbo ilẹ Yoruba wa ni abẹ àlejò, so it is better he is exiled to Ilorin to join his friends. 😌
Weldone oo Tanioloun. Get us the juju, apepa,eedi,sanponna ti yio pa awon ota Yoruba. We don't need to ague with mouth .Let us use Yoruba power to fight our enemies.
@@user-wu4su7br9i Omode o moogun o npe l'efo. Nkan ti awon agbalagba fi njeko, abe ewe lo wa. Nkan ta fi ju omode lo, a ki fi han, ta ba fi han, a ki fi le lowo. Gbogbo aso ko la nsa loorun. Ki owe je ti awon agbalagba. Ire o!
Ekotiri nkankan , oba oluwo ti so wipe Fulani Omo iya yin ni. Elo beere lowo awon Benue Ati plateau ohun to won foju ri ni pa gbigba won laaye tori esin. .
If you talk, they will say Islam. They should go and tell their Emir of Iwo nah why complaining? Las las, Una go learn the hard way. If they don't even collect the entire land from you ehn!
Mufti of Iwo and Oba Rasheed Oluwo said Iwo is Fulani land. So, expect nothing less. However, it's a pity that efforts at addressing herders problems and the food crisis can't yield positive results when mufti and oluwo are playing religion
Fulanis were having a welcome party for their emir. Iwo has fetched a firewood with many ants called emir Rashidi and mufuti iwo so it must witness the visit of lizards called foolanis
Eyin ara ilu iwo won sese bere si yin ni o.sebi nkan ti oba yin se fee ni yen eloba abudulrosidi oba yin kie lofi ejo sun.sebi awon family re ni awon Fulani.
Tani Olorun e kú ètò. Se kò sì akoya nile Yoruba mò ni?. E jeki awon agbe wá lo ṣe eto Yorùbá sí inú okò wọn.. Se bí ẹrí ohun tó sele ni ilu Ekiti ti ará bi sá pa gbogbo malu awon fulani. Ogun Fulani tí wọ ilẹ̀ Yorùbá e jeki a mura dada.
Is the work of your King .When you are ready the Town will do necessary things to your king.Fulani lose omo lya wa. Apaniyan no won.Oba yin lo nse yin. Oro ni gbogbo re Sebi Yoruba ni o .Oro ko lo ni lo Paws da Simeon.
There is nothing in this video to prove that this thing happened in iwo! It's lacking in substances required to be accepted as evidence. 1. It's not dated; the person who recorded it did not tell his intended viewers the date and time that he did it. 2. No mention of the name of the town or village where the video was recorded; the owner of the video failed to address this important information. 3. The police station and amotekun offices must have addresses; these addresses were not mentioned. While the efforts put into this video materials are appreciated, the facts remain that anyone who looks at the video critically, or reads the comments objectively, will see that it is compromised or biased. You have to have your proofs before you put anything out there; the source has to be reliable and credible. Learn from iya oloshun and Affa Okutagidi.
Oloye Sunday igboho was shouting crying thar we should all unite against this injustice against yoruba by fulani, some idiotic and bastard in our midst said that Sunday igboho should keep quiet. Now Sunday igboho is enjoying with his family in Germany while we are still here continuing in our complain...this is just the beginning
Gbogbo ohun ti won she si yoruba There can't try it in southeast just they are not in same page, until ti e ba fi esin won sile fun because you people will get rest
Eyin iwo egbodo complain oo, awon family yin lati ile hausa ti oluwo ko wale ni won wa kiyin. Obayin ni fulani ni ohun, eyin naa si gba bee nitori esin ati owo, Eyin ara iwo, eku tiyin. Ema losi police staion elo fi ejo sun Ana won Emir lwo to kowon wale
Yoruba Nation is chasing shadows. The idiot behind the attacked is olu iwo Rasheed Akanbi called himself emir. It's unfortunate the youths in ìwo are so slow in action to chase and remove him Immediately.
O se nrin awon Yoruba ni, ko i ti ja’won je. Ni igba ti o ba ge won je, won a parapo, won a dide OGUN ti awon Fulani ni ibikibi ti won ba f’ara pamo si ni Ile Yoruba. Won a bere lati ori Oluwo ati Muftau. O ku ise takuntakun o brother wa Tani Olohun.