Ekuse takutaku Oluwa Olodumare aranwalowo Amin o. Yoruba Nation no going back, Yoruba Nation now now now. God bless all Agitators for Yoruba Nation. God bless Prof Akintoye Adebanji, Chief Sunday Adeyemo Igboho Oosa and all people of Yoruba Land. Orilede Yoruba la fe ni kia kia kia. Ase Eledumare. God bless all people in house.
O maa pa Gani Adams lori adabi to ba ti je pe oun lo da EGBE O P C sile .laipe laijina lagbara Alawura alale Ooodua maa ye Gani Adams lese gbogbo awon eje omo yoruba ti awon fulani ti pa lo maa da Gani Adams lejo .
Oun gaan alara se baba Fasoranti yen fi omo won ti fulani pa si ore yen fi ra emii won ni ?abi kilo tie de na kilo nse awon baba agba iya wonwonyi na ?se awon ti won ti nwo inuu koto lo bayii niwon tun npariwo restructuring ?bawo ni awon baba wonyii se ya oloriburuku eda bayi ? Lagbara Olodunmare gbogbo yin lo maa seleya gbeyi aye yin lagbara alale Ooodua Amin ase.
Eku eto baba ekiti Mi beyin ema daruko ENI kankan sugban o gbogbo ENI ti o ba ni ki yoruba ma Kuro ni oko eru wan pare tirantiran pelu ogo olorun.ase ti gun yi lati ode orun.
Awan agba yoruba ko mon wipe baby ti seju.iyalenu loro awan baba yi ma unje fun awan ojulowo omo yoruba ,eyin baba yi ki lode ti ikan tiyin ki unte yin lorun
Awon Baba ti won ti de enu bode ti won yi wa owo kinni won fe fi owo na se, iru Baba Fashoranti ti won pa omo e ti o yen ki o ma pariwo Yoruba Nation ti ouna nwa restructuring awon agba oshi awon kidnappers awon Yoruba Gumi. Gbogbo won ni Olorun ma dajo fun.