Be ni o ma a ri, gbogbo adura na ha mo Adisa Omoaladikun Omo-Oko yoruba tooto owo baba dammy. Gbogbo awon ota Majasola ni oju ma a ti ni oruko nla ti Jesus kristy. Amin!
Amin ase edumare oti ribe oti se be ase orun ti gun ko si Yi pada Mon lae ati lae lae amin.gbogbo Adura ti akewi Yi gba sinu aye baba wa oloye Sunday igboho ossa.olirun ti mu gbogbo Adura naa wole ASE . gbogbo awon ota baba wa oloye Sunday igboho ossa ati baba wa professor banji akitoye loma siwaju won ku .baba wa oloye Sunday igboho ossa ati baba wa professor banji akitoye gbogbo awon ota yin loma siwaju yin ku .baba wa oloye Sunday igboho ossa ati baba wa professor banji akitoye iku ojiji iku esin iku gbigbona iku wahala iku airotele iku iponju iku kia kia iku plan iku motto iku oro iku oju orun ati iku oju ala ati iku oju aye Loma pa gbogbo awon ota yin danu tan pata pata ni ase edumare Amin.bi ota ko bi ota ko Yoruba lation ma duro gidigba ni ase edumare Amin.yoruba lation now now now no going back
E dakun ti ę ba ni awon video titun lati le fi gbeja oloye Sanday Igboho lori social media edakun ę send ę simi. Lati le fi se live fun awon eyan wa ni ede ketu. Awon video titun. Ę seun pupø.