Тёмный

ILABIRU, BABA OBO 2. (08/08/2023) 

IJINLE MEDIA
Подписаться 9 тыс.
Просмотров 3,4 тыс.
50% 1

NOTE: I HAVE NO COPYRIGHT TO THE VIDEOS I AM PLAYING ON TONIGHT'S PROGRAM. WELCOME TO MY CHANNEL. TO BE PART OF THE PROGRAMME, CALL +905367341665

Опубликовано:

 

7 сен 2024

Поделиться:

Ссылка:

Скачать:

Готовим ссылку...

Добавить в:

Мой плейлист
Посмотреть позже
Комментарии : 30   
@theophilusalao2030
@theophilusalao2030 Год назад
I can hear Olórí Kolotiti's voice. Happy to hear your voice. Ẹyin èèyàn mi, let us be motivated to reinforce our contributions to the Òmìnira 2022 account. SK419, you can't destroy a house built by God.
@titusfadebi6050
@titusfadebi6050 Год назад
Iyanu nla ni Olorun ma fi ohun ti Eweje yi se fun ijangbara ile Yoruba Nation.
@deborahadeniji4728
@deborahadeniji4728 Год назад
Yes 👍 Ominira Ade, Ekusee koni reyin loruko Oluwa, gbogbo emin awon alaisee pelu awon alale Yoruba yio ja fun wao ❤you all.
@josepholorunda6599
@josepholorunda6599 Год назад
God bless you ijinle and all people that want ominira Yoruba 2022and our mother moa in Jesus name amen
@toyinemiabata3502
@toyinemiabata3502 Год назад
Uncle Ijinle, God will continue to give you mouth and wisdom which your adversary who is also the adversary of Ominira yoruba 22 can't gain say in the name of Jesus Christ, Amen A mo iru won Sir. Gbogbio Eni ti ko ba nipa ati ipin ninu Ominira security support Olorun ko ni fi a ye gba won nitori iru won ma ta abawon si ododo Ominirs wa..ni o Abraham wipe " lest they say, they make Abraham rich" God will not allow any enemy of Ominirs Yoruba 22 to partake in the blessings and rewards that will follow those of us that believed and are in support of our race's freedom from Nigeria zoo bondage. More grace to all our Ominira Yoruba 22 leaders in the name of Jesus Christ.
@titusfadebi6050
@titusfadebi6050 Год назад
Iya yi ni Iyawo Loti, o boju wehin o di owon iyo, loba tan. Itan ti iya yi ko fun ara re niyi o. Alainironu iya, ko si pe mo ti san eleyi pee ohun to ba ti be jade mo gba folorun, ko si pe mo ti san e je ka gbagbe e. Owo yen o so wipe ibi ti nma de ko ni ki nma de be.Ko fi da awon ota loju, alagabagabe ni Iya yi o.
@titusfadebi6050
@titusfadebi6050 Год назад
Bibeli ni eni to ba fowo le ohun itule to boju wehin ko ye fun ijoba orun. Iya o mo itumo ohun to se. To ba mo itumo re, ni kankan o ye ko lo tuba, ko toro fun idariji gidigidi. Nigbati isele re ba de awon to ko ni Eko buburu yi o ni ba kedun o. E wo Kora, Dotani ati Abiramu oun to gbehin won ni irinajo won lo ile ileri.
@azezeadeosun6097
@azezeadeosun6097 Год назад
I lovely like this program share share
@ruthjoschua6547
@ruthjoschua6547 Год назад
Gbogbo oro ti won so si yin baba Ijinle e ma feti si gbogbo nkan ti won nso, won ran Olorun leti ,e ma wo ibe rara Olorun a ma wa pelu ati awon omo yin ati iyawo yin, owo ti ogede won ba gbe won ma fi na ara won ni, ni oruko nla ti Jesu amin.
@kunlesylvesterleye8190
@kunlesylvesterleye8190 Год назад
Baba Ijinle, e fi account ti ama da owo yen pada si ranse. Ọlọ́run a tun bo ma fun yin ni ọgbọ́n ati oye.
@morayoadams8848
@morayoadams8848 Год назад
Am happy to hear from Olori kolotiti. You are welcome ma❤
@titusfadebi6050
@titusfadebi6050 Год назад
My brother, though I don’t know your name, there is no need to refund the money just wait and see what God is going to do to bro Ijinle about this simple action, ten times blessings is coming to him. On the other side also, see the way God is going to use His whip I mean whip on everyone of them. Their suffering will be too much and is at hand.
@ayankoyaoluwayomibo8745
@ayankoyaoluwayomibo8745 Год назад
It's good as ijinle returned her money , such one are among those that will be saying that they embezzle their money , the truth will prevail soon , shame on them, they are soyekoribe fans ,propably they are finding means to tarnish the image of ijinle
@deborahadeniji4728
@deborahadeniji4728 Год назад
Olorun yio si masee iranlowo fun Ijinle ati idile re , ibiti owo yen ti jade abudi niti odo, iyemeji ti awon eniyan nse naa ni koni je ki won ri ire ijoba ile Yoruba.
@GbemisolaOgungbemi67
@GbemisolaOgungbemi67 Год назад
BẸẸ NI ÒÒÒ BÀBÁ BLACK LION, KO SI BÀBÀ SỌPE NINU IRIN ÀJÒ YORÙBÁ NATION, TORÍ ÒTÍTỌ́ ÀTI ÒDODO NI WỌN FI GBÉ DÚRÓ, KO SI ẸDA KAN TÀBÍ NINU ÒBIRIN TO LE DÁ ÌṢE TÍ ỌLỌ́RUN TÍ PARÍ LÁṢẸ ÈDÙMÀRÈ
@titusfadebi6050
@titusfadebi6050 Год назад
My belief is that the woman was at the other side of Yoruba struggle group. They have confused her, this mama is the person bible refers to as the seed that fell on the road that foot trampled and died. Or the ones that fell on the rock that died because no water, that is that woman. Being an elder does not mean their gumption is correct, their thinking is right.
@ayankoyaoluwayomibo8745
@ayankoyaoluwayomibo8745 Год назад
She didn't stay with the truth media, she goes from one media to another that's the reason she was confused.
@GbemisolaOgungbemi67
@GbemisolaOgungbemi67 Год назад
Hummmm, màmá to pé wọlé yí, ọgbọ́n orí yín kò ní doba láṣẹ Èdùmàrè
@morayoadams8848
@morayoadams8848 Год назад
Pls invite Olori kolotiti to your show
@novolasmty
@novolasmty Год назад
Ogaooooo Edumare tete wa gbawa o
@theophilusalao2030
@theophilusalao2030 Год назад
How much is N20k by the way that someone will be ranting that she needs her money back? That money is not enough to cook a good soup in Yorùbáland currently. What does she want those who have donated $25k and more? Shame on Iya Ewenje àti SK419. The money will soon be complete and Adele máa wọlé!
@titusfadebi6050
@titusfadebi6050 Год назад
Sir, forget about being educated or not. Many of our educacated brothers and sisters whose their thinking is low, they never see the future, even they never believe in Yoruba Nation. I said it in this platform that it was in the year 1996, I went to my uncle at Ore I told him I came to see him. He said okay, I asked him why did Baba Awolowo not declared Yoruba Nation when Biafra war started. My uncle said is not easy the way am looking at it. The belief of most of our people is that it cannot be possible to get Yoruba Nation. Awon alainigbagbo, awon ti o mo Olorun. I read Nigeria five Majors novel by major Adegboyega, there was a country Biafra by Chinua Achebe, a lot of novels and yesteryears of daily news papers where I read about this country to show that we are not one and cannot settle except we go our different ways.
@princeolubukolaalabi1898
@princeolubukolaalabi1898 Год назад
Where is olori kolotiti please. We want her on ijinle show.
@omotayoajayi211
@omotayoajayi211 Год назад
Brother ljinle a dara fun yin lya yi ti yo oruko nwon ati idile nwon kuro ninu iwe iye. Sugbon ki Iya yi ranti pe ko si ona abayo mo
@ruthjoschua6547
@ruthjoschua6547 Год назад
Soyekojale lo ma bere lori eto re wipe tani o gba on ni eti, awon alale ti beresi gba ni eti ti ko fura.
@ruthjoschua6547
@ruthjoschua6547 Год назад
They are all 😤 frustrated already.
@princeolubukolaalabi1898
@princeolubukolaalabi1898 Год назад
Is olori kolo titi in the show.
@omotayoajayi211
@omotayoajayi211 Год назад
Oruko Iya yi ti kuro ninu iwe iye
@user-xd8vc4oc7o
@user-xd8vc4oc7o Год назад
Please send me the naira account sir
@ruthjoschua6547
@ruthjoschua6547 Год назад
Mama wa Olori kolotiti who slap you ma?
Далее
Fixing Plastic with Staples
00:18
Просмотров 1,3 млн
RCCG HOLY GHOST CONVENTION 2023 -  PLENARY SESSION 2
3:53:00
Majemu Imugbooro ( Covenant of Expansion). +2348134285455
1:39:55
I TOLD YOUR WIFE (With Mr. Macaroni)
3:35
Просмотров 74 тыс.
The power of Noble Association | Gateway to Nibbana
1:42:09
Elul: G-d Is Speaking To Me - Rabanit K. Sarah Cohen
1:10:16
Will We Rise From The Ashes?
57:04
Просмотров 1,7 тыс.
Dear Mr Starmer:   Subject: Islamophobia
7:33
Просмотров 82 тыс.