Тёмный
No video :(

IMAMU EGBA,IROLE YIN YI KO FE DARA TO PAAPA,LATARI EPE TI E NSE FUN SOUN OGBOMOSO: 

ImoleOnlineTv
Подписаться 1,1 тыс.
Просмотров 4,4 тыс.
50% 1

Опубликовано:

 

24 авг 2024

Поделиться:

Ссылка:

Скачать:

Готовим ссылку...

Добавить в:

Мой плейлист
Посмотреть позже
Комментарии : 89   
@aminuphilip1841
@aminuphilip1841 Месяц назад
Mo ki Oba Ghandi Soun Ogbomoso kuu suuru, ipamora, ogbon iwa agba ati fifi apeere onigbagbo tooto han. Ki Olorun otito jeri ara re lori oro yi. Amin.
@deboodepe8062
@deboodepe8062 Месяц назад
Amin. Amin . Amin.
@deboodepe8062
@deboodepe8062 Месяц назад
Isaiah 59:8 " The way of peace they have not known. And there is no justice in their ways. They have made themselves crooked paths; Whoever takes that way shall not know peace." Awa Musulumi egba, Mufti Iwo, ati awon ari otito ma wi, eko wo ati awomani wo n le n ko araiye?
@olusholaadegoke4370
@olusholaadegoke4370 Месяц назад
Omo Ale Ogbomosho ni inu re yoo dun ti won ba bu Oba wa Logbomosho,
@adeyemimuhammed3232
@adeyemimuhammed3232 Месяц назад
Ọmọ ọkọ Ogbomosho ni Bàbá yí!
@najimudeenhabeeblah6646
@najimudeenhabeeblah6646 Месяц назад
You go explain tire Baba😂😂😂
@fataisanni7106
@fataisanni7106 Месяц назад
Taofeeq, ìwọ gan loun da wàhálà si lẹ̀ ni Ogbomoso. Ki lo de ti oun sọ fun Ọba ko maa jẹ ki ọ̀rọ̀ naa pari. Se o ni nnkan to fẹ́ gba nbẹ ni. Nnkan to n se ẹ́ ni pe. O ti ri ede aiyede yii si ere ije. O wa n fẹ́ ki awọn group ẹ win. Ọ̀dẹ̀ ni ẹ.
@ditty6828
@ditty6828 Месяц назад
Iro lo pa fun yen. Se Taofik Lobanika lo tun ni ki imam yin tun lo fi ejo oba sun baba elepe imam yen, abi e fi owu elepo si eti ni? Kilode ti majority eyin isilamu o se ni laakaye ba'i?.
@akindelegiwa5874
@akindelegiwa5874 Месяц назад
Amin
@IbrahimOlayiwola-nx8oc
@IbrahimOlayiwola-nx8oc Месяц назад
Iman yoo bori gbogbo yin ni agbara olorun
@AlomaIbrahim
@AlomaIbrahim Месяц назад
walahi dajudaju imam talhat ayilara kise omo ogbomoso pelu ountimogbo lenu imam agba ile egban imam talhat kise omo ayilara
@SerahGibson
@SerahGibson Месяц назад
Sebi enia na loda man to nsoro yi, se ohun ti nwon nfi aiye nwon se, ina Olorun ma jo baba yi kale ni. Idajo iro, ika, ailotito,nigbati kisepe enyin le da ara nyin. Gbogbo awon enia oran bayi, ki Olorun ti o da aiye on orun, ki o kolu nyin.Gbogbo awon ti onmu iro wa ba nyin, ti eo wadi ohun gbogbo daju. Kinide ti eni ika ninu, gbogbo eda ti onsika omo lakeji, Olorun toni aiye on orun yio kolu nwon. Why ti ako ma wa bi Olorun yio se se gbogbo wa laanu.
@aruwewetv6018
@aruwewetv6018 Месяц назад
So he thinks he's that superior to the extent of dictating for the king to return home from his journey but the king has no right to know about Imam travelling??? Nah wha ooooo
@deboodepe8062
@deboodepe8062 Месяц назад
E ba mi bi won o. Abi eo ri n kan bi??
@isolawasiu2718
@isolawasiu2718 Месяц назад
Baba LOBANIKA, WARAFANAHU MONKANA HALIYA
@adeyemimuhammed3232
@adeyemimuhammed3232 Месяц назад
Ọmọ Onílù kò ní fẹ o tu!
@fataisanni7106
@fataisanni7106 Месяц назад
Ìwọ Ọmọ-kùnrin yii... O ni ọgbọ́n ati òye láti maa sọ̀rọ̀ fun àwọn ara Ogbomoso. Nítorí mo ri wípé ó korira Tọlihat ni. O si ni o fẹ ri Baba yẹn fin... Igberaga lo n daa ẹ laamu, lati maa ri Imam fin.
@deboodepe8062
@deboodepe8062 Месяц назад
Se iro ti ri ti o n pa? Omo iya wa ni ogbon o! Koda ori re pe ju tire lo.
@adeyemimuhammed3232
@adeyemimuhammed3232 Месяц назад
Se iwọ náà lè ṣe nkan ti Ọkan Tolihat nṣe yi?
@aadeoyemosun0359
@aadeoyemosun0359 Месяц назад
Baba eku ise.olohun yoo san yin lesan lori Imam Taliat
@deboodepe8062
@deboodepe8062 Месяц назад
Ewo bi baba lemomu egba n soro bi Olodumare!!! Ah! E si wadi oro ki eto ma se'pe? Sugbon ari wipe ball owo ti Toliat gbe fun yin lo n soro😂😂😂
@OWOADENAFISATBOLANLE-nu7ey
@OWOADENAFISATBOLANLE-nu7ey Месяц назад
Baba en se tanadi Omo olomo esi pe ara yin ni musulumi bi won o se ti Omo yin ni yen
@RhamanWasiu
@RhamanWasiu Месяц назад
Ekuu ise olorun babawa lobanikaa koniireyin alubarika anabii Muhammad
@AzeezOla-jw2ry
@AzeezOla-jw2ry Месяц назад
Baba were agbaya buruku esan Ake Lori yin pelu ogo olohun
@user-ch3dj6fn5f
@user-ch3dj6fn5f Месяц назад
Won ni agba ki wa loja kori omo tuntun o wo. Agba baba Imanu Egba ko tole rara. Mo wo interview kan ti Benbeyeke se pelu baba yi. Oro ti won nso le da gbogbo ile yoruba ru. Nigbeyin, baba yen je ka mo pe ija esin lawon nja. O ga o
@aadeoyemosun0359
@aadeoyemosun0359 Месяц назад
My advise for you siris to use your time to be preaching word of Allah on social and you will be rewarded here and hereafter.
@OladepoNurudeen
@OladepoNurudeen Месяц назад
Were agbalagba
@maryogunsina5066
@maryogunsina5066 Месяц назад
Babalawo pataki ni baba umami egba yi , awon Alfa onikundi
@user-ov9mc3iu1i
@user-ov9mc3iu1i Месяц назад
Baba Taofeek, you're very funny .please try to give yourself the rest of mind
@maryogunsina5066
@maryogunsina5066 Месяц назад
TELIATU omo ale
@maryogunsina5066
@maryogunsina5066 Месяц назад
Tu ile tu ile ni baba umami egba yi , oloogun paraku ni baba arugbjo yi o
@arinolamayaki7487
@arinolamayaki7487 Месяц назад
This man always speak the truth.
@ditty6828
@ditty6828 Месяц назад
But they don't want the truth.
@Kabisanra
@Kabisanra Месяц назад
Baba o le gbo were re oooo iwo were yi
@olayinkasanusi5978
@olayinkasanusi5978 Месяц назад
I wish this boy knew the Imam of Egbaland. But incase you don't know the chief of Imam of egbaland will feed your generations even before he became the chief imam of egba land.
@deboodepe8062
@deboodepe8062 Месяц назад
Pelu yara kan ti o fi yara, parlour ati bed abi?
@aruwewetv6018
@aruwewetv6018 Месяц назад
So by just being called by the king to demand why leaving the state without telling his principal, so this Imam can go this route to ridicule his principal???? Is it not this same Imam of Ogbomoso that forced the king to cancel his flight from travelling few months ago???
@kolataiwo2
@kolataiwo2 Месяц назад
This is not a charitable statement from the imam of Egba despite his age. I think that Toliat is not likely to be from ogbomosho. A real son would never allow anyone no matter how old to abuse his heritage. Some imams are poorly trained and lack religious wisdom.
@user-kp1yj8go8o
@user-kp1yj8go8o Месяц назад
Didirin, agbalagba, are they supposed to take permission from you?
@ditty6828
@ditty6828 Месяц назад
Nkan ti mo kan mo ni pe, eni to ba wu iwa epe ki gbogbo aye ma gba'dura fun, epe ni won nse fun. Eni ti adura to si sugbon ti awon alabosi ati alaimokan ngbe se'pe, adura ni won ngba fun.
@SimisolaOyewole
@SimisolaOyewole День назад
@@ditty6828 Pele o, eni ti o ni bibi. Sebi abuku ti o ma ma kan,na lon kan yen, won ti so fun e wipe o ki se omo ile Ayilara atipe iwo lon da inu ebi Ayilara ru.Lo wa ise se, ilara lon se e.
@Fattylincorn
@Fattylincorn Месяц назад
Why are you threatening Violence ? This is not good mr Lobalewon
@semiouokpeicha
@semiouokpeicha Месяц назад
Èsi bèru Allah
@akintundeokelade2563
@akintundeokelade2563 Месяц назад
God is not wicked
@Fattylincorn
@Fattylincorn Месяц назад
Baba shey eyin lefe ta eje awon eyan sile ni ilu Ogbomosho?
@SimisolaOyewole
@SimisolaOyewole 2 дня назад
Iro po lenu Lobanika
@zubairmuhammad608
@zubairmuhammad608 2 дня назад
@@SimisolaOyewole a'i ni bibi re si po ninu iran tie na.
@brightay0078
@brightay0078 Месяц назад
No any weapon, curses, fashions against Ghandi shall NOT prosper. They should tell this Baba that except if he didnot have his children or grand children
@adexadexd1
@adexadexd1 Месяц назад
English
@brightay0078
@brightay0078 Месяц назад
@@adexadexd1 Prof. Wole Shoyinka, i just asked my kid of pry three to respond to that while i was driven so, yours can do the same as well. Prof of English
@adexadexd1
@adexadexd1 Месяц назад
@@brightay0078 Still English
@brightay0078
@brightay0078 Месяц назад
@@adexadexd1 You re just a big fool.
@fataisanni7106
@fataisanni7106 Месяц назад
O ni ìṣòro tó pọ̀ gan. What's your problem cos u are not member of Ayilara family.
@SimisolaOyewole
@SimisolaOyewole 2 дня назад
Kin lon kae lara ninu oro oloro?
@gasteeroy8518
@gasteeroy8518 Месяц назад
The way tailat is going about this issue shows he's omoale, he's not true born of ogbomoso. Any true born will not be doing this to the king of his own town
@HamzatRasheed-ut1ts
@HamzatRasheed-ut1ts Месяц назад
Well done sir
@RhamanWasiu
@RhamanWasiu Месяц назад
❤❤❤❤❤
@Kabisanra
@Kabisanra Месяц назад
Olori buruku ni TAOFEEK yi oooo
@deboodepe8062
@deboodepe8062 Месяц назад
Olorirere ni Taof
@aminuphilip1841
@aminuphilip1841 Месяц назад
E jowo kilo de na ti awon agbaya, tikunloju arijenidibaje ko tii tan laye ? Kiyesii esan a ke.
@SirG_world
@SirG_world Месяц назад
The man is old, but the presenter was asking those without applying wisdom,I want you to check the video again I don't know maybe the presenter is working on contract basic all his questions was not from peace at all
@ramotaabiolaraji1041
@ramotaabiolaraji1041 Месяц назад
Lobanika don't kill yourself on Imam's matter. Arije nidi modaru ni e. Baba Imam Egba ti toro aforiji lowo Oba soun won si tun se adua fun won. For your information, the misunderstood you caused between Oba soun and Imam has been settled.May Almighty spare the life of our King for goodness likewise Imam.
@hammedolaniyi4007
@hammedolaniyi4007 Месяц назад
So, lobanika has no any job, every minute on media to fight what you can't win. Agbalagba adaluru.
@adeshinaalamu6955
@adeshinaalamu6955 Месяц назад
You are stupid ,you this guy ,you are taking to leader baba lobanika ori yin wa nbe sir keep on moving sir.
@ditty6828
@ditty6828 Месяц назад
Seems you are affected and pained by what his saying because you hate the truth. The man wants peace for his homeland - heritage.
@Fattylincorn
@Fattylincorn Месяц назад
He's jobless man😂
@rasaqjelili
@rasaqjelili Месяц назад
You will need 1 million videos before people will understand you,baba you will explain tire
@Fattylincorn
@Fattylincorn Месяц назад
😂😂😂😂
@abdulawwalabdulwasiuadewum5941
@abdulawwalabdulwasiuadewum5941 Месяц назад
Abi o
@Jimmysteeve
@Jimmysteeve Месяц назад
Oloriburuku. Majority of you hide under yoruba name but you are fulani in characters. Shame on you
@maryogunsina5066
@maryogunsina5066 Месяц назад
All these nonsense you are performing with Soun, if Soun should be Muslim I am he would have dealt seriously with you these vagabonds in religion u( RELIGION OF FORCE) Imonle.
@maryogunsina5066
@maryogunsina5066 Месяц назад
Awon elesin jagidijagan, esin apaniyan anabi ni ki e pa won.
@AzeezSefiu-q5l
@AzeezSefiu-q5l Месяц назад
Well done sir
Далее
Ababo ile ejo laarin pastor ati awon Alfa
13:50
Просмотров 25 тыс.
IMAMU EGBA ATI IMAMU OGBOMOSO E SUN MOBI !!!
58:56
Просмотров 2,5 тыс.
'The Mistake Bola Ige made' on Trouble Shots Episode One.
1:38:59