Eya ara ti osoro lati toju ni ori je, bi kose rorun lati se ori buruku be nanni ko rorun lati se oriire. Eru ti ori gbe o po gan ni, oju, imun, eti, ahon, eyin, enu, opolo, ati be be lo. Moki olopa wa dara dara, nitori wipe ibiti ori re sin de niyen. Ori ni aisan ti onse Naijiria, arun ti ko gbo ogun sini ori je, ti eleda eniyan ba gbabode ori na ni ama npe ni eleda, inu awon oga olopa kole dunsi nkan ti lbrahim se yio nitori atowodowo ni owo yen, won ti lbrahim ni, ni nireti wipe ninu owo yen npada bo wa si inu apo tiwon na, ki lbrahim sora o, nitori wipe won ma gbe kuro ni ibiti owa yen losi ibomiran laipe.