I heard about this woman while growing up in Ilesha. Very powerful woman, and I’m so happy how Ijesha people took her, imagine she’s from Modakeke but you never can tell that she’s not Ijesha. This woman is 1 of the powerful people that used jazz pursued 419 people in Ilesha over 20-25yrs ago…
Am proud of this mama for not hiding herself that's how is should be, people should worship what you believe that can give you peace in your life, not another religion from another country
Mama e dakun e ma gbadura fun mi ki gbogbo nkan yipada si dada fun mi ni ajo ti mo wa yi. Ki ni akojo ati aseyori NLA lopolopo ni gbogbo ona mi 🙏🙏🙏 ati aburo mi ti a jo wa si orilede Togo ni Lome ti awa yii ni agbara Olorun Oba Edumare 🙏🙏🙏
Mama wa e ku ise takuntakun, Eledumare a wa pelu yin ati awa naa amin 🙌🙌🙌 Mama mo fe ki nmo yin o mama mi dada. Mi o si nile bayi, e gbadura fun mi mama ki ajo ti mo wa yi ki o gbe mi, Amin Ase Edumare 🙏🙏🙏💖💖💖 Gbogbo igba ti mo ba wale ma de odo yin, ki Olorun Oba Edumare 🙏 bun wa ni emi gigun ati alafia 🙌🙌🙌❤❤❤❤
Iya Yi need Jesu o. Ti iya Yi ba ku bayi Inu Ina aiyeraye ni o. E bere lowo iya Yi pe ti iku bade bayi nibo ni iya yi nlo? Tani Eni to wa ki iya yi to wa, nibo ni eni wa, E so fun iya yi pe kio kuro ninu okunkun. Kio wa sinu imole Jesu Christi kio ma ba kabamo to ba ku.