E joo sa, E bawa se ayewo awon opo awon a' ye deru pasito ti won wa si ori oke dada. 2012, baba wa Samuel pasito niwon,omo ido ile niwon. Baba ori oke niwon, Pasito nkan wa lati ilu ibadan,orisirisi ogun ni o kowa, Pasito Samuel ni Oluwa fi arahan pe iranse kan wa pelu wa,pe o gbe OGUN wa.. Pelu oore ofe Oluwa arakunrin jade pelu ina adura . E joo,opo awon irase esu,ti won pe ara won niranse Olorun, e ma se aye won dada.
Abiyamo o . Eleyi buru jai, alaboyun, pelu omo inu re. E jowo kini apapo ijo ma se si awon ijo ton huwa bayi ti won nfi church boju se ise ibi. Iwa buburu ti npo ju o.
Babalawo mélòó ló ti pa ìyàwó wọn. You guys are found covering your evil act and put it in on our tradition.. Alábòsí ni gbogbo yín the man have mental problem which has nothing to do with religion
How come when he's a babalawo he didn't kill anyone? Now oti losi esin ajeji esin tokunbo esin jagidi jagon esin alakataki owa gba emi eniyon as an evergelist you are serial killer not babalawo kill like you evergelist or pastor. Stop lying against ISESE