Yes if I am looking for his downfall I agreed I am not a Muslim,but what about going against for taking what does not belong to him, just give a judgement that you can defend before ALLAH.
@@AkanoSulaimon ireje babanla baba re lo pami lekun,egbere,Pelu ogo Olorun gbogbo ise tio fi igbesi aye re se ni oni jere re ayafi ti mo ba doju oro mi ko babanla baba re kio to bo si ori agbagbin yi,omo ofo,omo ko si nile inu iya ndu omo wole de inu baje, o ni jere ara re mo lati oni lo OLA TABATYADA 111×, moti ba o se bayi bayi.
Abi ewawo Baba akumo mojudi yii biti nsepe bi okete!!! Oga o ti eyin naa sibi omo tiyin!!! Emio jeyin lepe. Sugbon ti aba leni ti aoba bani,sebi eeyan yiosi pada, efi imom yii sile ejeki osetie,towaje lori wahala yii naani ewa. Se eyin nikan lenbe ni ogbomosho ni? Abi kini wahala aye yin gan an? Kini ode ti egba kadara gbo? Ti ewa fi ewu ori se keeta omo inu yin. Oga o ,agba koni ogbon o.@@zubairmuhammad608