Awon Oloselu Nigeria won mo bi won se ma n tan awon Ara ilu Nigeria. Ki ni de ti won tun mu Aso Ebi fun Owo ifehin ti. Se won ko ni acct number ni. Asiko Ibo miran tun bo. Ko si iru yen ni Odo ti wa ni ilu yi rara.
Eyin oselu nyin ewo bi ese fi emi awon Omo tebi sofo danu nitori joko oloriburuku ole yii ... Awon omo oloriburuku egbe okunkun telo naa ni won pa awon omo yii danu.... Were arayin ewa ko awon olopaa ilu Nigeria sinu wahala.... Osinwi ni nyin