We seek your support. Our vision is to bring #Masoyinbo to communities across the southwestern states of Nigeria and beyond, fostering both enjoyment and awareness about preserving our language and culture. Please consider following this link to offer your support. Ẹ ṣeun gan ni, a dúpẹ́!! buy.stripe.com/fZe5l83Rx72k3m08wz
Ẹ kú ètò sà, yóò máa jú u yín ṣe lọ́lá Olúwa. Èdè e wa àṣà a wa kò ní parun láṣẹ Èdùmàrè. Tiwa làṣà, tiwa n'ìṣẹ̀ṣe Ẹ kú ìfọmọ-nìyàn-ṣe ❤ Yóò dùn mọ́ mi nínú púpọ̀ bí èmi náà bá lè wá sórí ètò pàtàkì yìí. Ẹ ṣeun ṣeun ❤
Never he will surely make mistake oooo The man won't even allow him to win it Do u no alot of Yoruba teachers that are here that did not even collet up to 100k)