The lady that came during the last episode would have answered most of these questions conveniently. I guess the presenter was determined to make her fail some questions since she's a Yoruba Presenter. Good job EA YORUBA
😂😂😂😂 Arábìnrin yìí gbìyànjú àmọ́ ṣá, omi òǹkà àti àmúlùmálà èdè rẹ pọ̀ ju ọkà lọ 😅 Atọ́kùn, ẹ kú ìfọmọ-nìyàn-ṣe, Èdùmàrè yóò máa fún un yín ṣe, bákan náà ni mo kí olófofó kú iṣẹ́ takuntakun 😅 ẹ̀rín rẹ máa ń pa mi lọ́tọ̀ ni. Ọjọ́ kan yóò j'ọ́kan tí èmi náà yóò wá sórí ètò pàtàkì yìí, nǹkan yóò gbé nǹkan há'nu lọ́jọ́ náà 😂
Olootu and olofofo will bite and blow air into the wound so that you won't feel any pain. Won a fi oyaya throw you off balance😂. E kare, e ku ise takuntakun. The show is educating, keep doing the good work.
You don't come to this program with too much confidence, you will become humble. The starting also destabilize her and made her lose her watchfulness of the use of english in conversation. She could do better another time. She has the potential
E jọwọ Olotu wa masoyibo a n gbádùn eto yin daradara sugbon ọpọlọpọ awọn alejò yin n gbìyànjú sugbọn ònà tí e gba fi já won ti pọ ju,e le ma fún won ni awọn onka yen lofe ki e si ma je ki wón ri nkan mú lo sílé nítorí owó okò won,kí agara ma ba ma dá àwon alejò yin,E seun olootu fún akiyesi wa.