Тёмный

MIDNIGHT PROPHETIC PRAYER || LIVE || PROPHET SAMUEL ADEBAYO OJO (BABA AUTHORITY). 

oriokeogo official
Подписаться 18 тыс.
Просмотров 1,8 тыс.
50% 1

MIDNIGHT PROPHETIC PRAYER || LIVE || PROPHET SAMUEL ADEBAYO OJO (BABA AUTHORITY).

Опубликовано:

 

17 сен 2024

Поделиться:

Ссылка:

Скачать:

Готовим ссылку...

Добавить в:

Мой плейлист
Посмотреть позже
Комментарии : 18   
@OluwasegunPeter-v1m
@OluwasegunPeter-v1m 21 день назад
I connected myself and my job in to this prayer in Jesus name amen
@adeyemiileaje4238
@adeyemiileaje4238 21 день назад
Amin Jeeesu
@adeyemiileaje4238
@adeyemiileaje4238 21 день назад
Ilekun next level si fun mi, si fun awon omo mi loruko Jesu, awon omo mi gba oore tuntun, won gba aanu tuntun, CV omo mi parada o di ise aanu ati ise ifokanbale loruko Jesu
@HelenOkeyemi
@HelenOkeyemi 20 дней назад
I connect all my family with this prayers
@IfeToyosi
@IfeToyosi 21 день назад
I collect myself and my children and my husband and my family to the blood of Jesus
@adeyemiileaje4238
@adeyemiileaje4238 21 день назад
Olorun Authority ooo, gbogbo emi okunkun to n yo kele wa gba ire awon omo mi loganjo, iku pa yin loru oni, ida ina Olorun sa yin pa loruko Jesu, e so agbara yin nu lati iseju yi loruko, orun koju ija si yin, angeli ibinu Olorun kolu won, o run won danu loruko Jesu, aye awon omo gba isinmi, annu ati ojurere to to si won loruko Jesu
@DanielComfort-j4o
@DanielComfort-j4o 20 дней назад
I connect myself in Jesus name
@adeyemiileaje4238
@adeyemiileaje4238 21 день назад
Ni oruko Jeesu, iseda mi, iseda awon omo mi gbo oro Oluwa, jade ninu yara iku, a wo yara iye loruko Jesu, iseda mi ati awon omo mi wonu yara iye, yara aanu ati igbedide, yara ojurere lo loruko Jesu
@tolulopeadebiyi3577
@tolulopeadebiyi3577 20 дней назад
I connect my life my marriage to this program ijn.
@adeyemiileaje4238
@adeyemiileaje4238 21 день назад
Ohun rere gbogbo ti awon omo mi n reti, aanu gba pada fun won, owo ati iyanu ti won nreti, Oluwa fi aanu gba fun won, dari oloore ati alaanu gboogi sinu aye awon omo mi loruko Jesu
@adeyemiileaje4238
@adeyemiileaje4238 21 день назад
Eyin agbara to ni mi o ni ojo ayeye ati aseye lori awon omo mi, ni oruko Jesu, e wo iboji lo lati oni, e ku ki e wo iboji lo loruko Jesu, eyin agbara to ni awon omo ologo mi ko ni fohun nibi giga laye, ni oruko Jesu, ara orun san pa yin, e sare wo inu iboji lo loruko Jesu
@adeyemiileaje4238
@adeyemiileaje4238 21 день назад
Emi iku lara mi ati awon omo mi ba ina jade, gbogbo agbara emi iku ninu aye mi ati awon omo mi, jade pelu owo agbara loruko Jesu, iku ati awon iranse won, e poore niwaju emi ati awon omo mi loruko Jesu
@adeyemiileaje4238
@adeyemiileaje4238 21 день назад
Ni oruko Jeesu, ofa idaduro ati ifaseyin lara emi ati awon omo mi ba ina jade loruko Jesu, gbogbo ojukan lara emi ati awon omo mi jade pelu owo agbara Oluwa, owo ojukan jara lara mi ati awon omo mi
@adeyemiileaje4238
@adeyemiileaje4238 21 день назад
Gbogbo agbara to ni mi o ni kuro ninu ogun tomotomo, o ya e sofo danu, eyin emi buburu to ni mi o ni bo lowo ogun ati awon omo mi, o ya e sofo, e wole, ki e tuka, e kanju wo saare lo loruko Jesu, agbara ojukan lori awon omo mi, ni oruko Jesu, e pare, e wole, aye awon omo mi gba itusile, won wonu ogo tuntun lo loruko Jesu
@adeyemiileaje4238
@adeyemiileaje4238 21 день назад
Gbogbo awon to mo feyinti to won tun n fi ogun ja mi ati awon omo mi, Oluwa dana iku le won lori, orun roju ibanuje sinu aye won, eni ti mo fokantan, to n ja aye mi ati awon omo mi logun, Oluwa ba mi fi iku kolu won, ba mi run won danu loruko Jesu, ki aye mi gba isinmi tomotomo
@pierreagani6895
@pierreagani6895 20 дней назад
Mo bere fun igbega l'enun ise mi
@AdenayaGaniyat
@AdenayaGaniyat 21 день назад
Loruko jeesu ofa idaduro ati ifaseyin ninu ara mi ati awon omo mi ina gbe jade loruko jeesu amin loruko jeesu
@adeyemiileaje4238
@adeyemiileaje4238 21 день назад
Olorun Authority dide fun iranlowo mi ati awon omo mi, ohunrere ti a nreti, Oluwa je ko to wa lowo, fi aanu da si oro aye awon omo mi, se oore agbayanu ninu aye won, ibi ti a ti nreti iranlowo ise rere, Olorun Authority pase ise rere fun won loruko Jesu
Далее
ГОЧА ПРО NISSAN 400Z
00:51
Просмотров 40 тыс.
Hebrews, Session 13, September 16, 2024
55:32
They worship God in vain
3:04:24
Просмотров 101 тыс.
DIVINE ASALATU
1:12:38
Просмотров 291 тыс.