Olorun Authority pase igbedide sinu aye awon omo, pase aanu ojurere si aye mi ati awon omo mi loruko Jesu gbe iranlowo ojiji dide fun emi ati awon omo mi loruko Jesu
Olorun Baba Authority, jare pase alaafia sinu aye awon omo mi ni wakati oru yi, je ki aye won gba alaafia, gbogbo ogun iba ati ara riro wo ile lo ni iseju yi, loruko Jesu, ki won gba imularada ojiji ninu ago ara won loruko Jesu
I connect myself Ayoni Dare Funso Bukola Kehinde Christian Justin fiyinfoluwa Tolu Ireoluwa to this prophetic prayers of PROPHET SAMUEL OJO. ...BABA AUTHORITY....IJMN AMEN