“Omo Ale” will definitely behave like one. So rude, so arrogant. Go back to Ayilara family to prove your paternity. You came in to occupy this position thru back door. Definitely you will go out thru the Window.
So arrogant and full of himself. He's too disrespectful and uncouth. I wonder hiw this one will be a town's religion leader... it's too bad. Asiyan gba ni fun ilu ogbomosho
@@AkeekOmoola ore ise tio bafi aro osan se oni je,awon omo re na o si ni ri nkankan de ba,ti asiko ba wa to eni eleni ni yio jogun ise ti o ba se,lati inu sare re ni wati ma ri,ti omi oju re o si ni da.
Oloriburuku ni e lobanika adarugudu nie kini imam wi toti buru ju wipe Kristian o mo nipa esin wa sugbon nigba tojepe musulumi elebo nie lo nse se ote pelu imam Ogbomosho, sugbon ranti o atubotan re oo
@@OladepoNurudeen Se esin na lo ko kio ma bu eni ti nkankan ko payin po,o da oooo babanla baba re tio ba ti ku koni da fun,ti baba re basi wa laye koni ku re,iwo fun rara re oni jere ara re ola Suratul Fil,bio se ka yi ati gbogbo eni tio ba ka esi oro re yi amin summa amin kunfayakum.
@@zubairmuhammad608 Koni dafun e oloriburuku se esin Loko iwo ki o ma sepe fun odidi imam ilu awon Omo re oni simi bi ovse da imam laamu yen iwo naa o ni simi
@@OladepoNurudeen abi siwin,omo ole,alaini eko,bi igbesi aye re yio se ri ni mo ti so un,lati asiko yi lo oni fi ese ko mo enu ni wa fi ma ko,o si ni bo nibe ola TABATYADA.........11 pere,ma worry ma bae ke hutuba re lofe pelu ogo, Olorun,awon jama'a wa nibi ni TAHJUD ti se sara re fun o,kosi ni dawo duro pelu ogo Olorun,ma palemo sise sise ti yio ran o nise alo made pada si arin awon eniyan gidi.
@@zubairmuhammad608 oloriburuku ni e se iwo ti o le se adura fun ara re ki adura re gba oni o n sepe fun enikan were agbalagba to o sepe fun odidi imam agba o mope egun ayeraye ti ba e ti kosilee sin lori re ati awon Omo re laelae, otun ni iyawo nile agbalagba oponu. Tiwon bi dada drop number ki emi ati e kapade ki o mo iru eniyan timo je
Eyin werey omo eru, so this is called ododo calling someone that is old enough to be his father by name just because he's the Imam and also insulting the ladani imagine this arrogant fool
@Kabisanra so you support all these rubbish for a supposed religion leader? Where I the peace that Islam teaches us? Where is the imam's patience? Instead of calling people to the ways of Allah he's dishing out arrogance on minbar. He keeps showing he lacks manners and proper home training. Iwa ati ikose anobi SAW o si mi ara imam toliat. He's writing a bad history for himself and is future generations to come in that town. You people continue to hail him to destruction. Instead of seeking peace for him.