Well done sir,an adage says friendship is not by force is by choice.up Yoruba nation,up Baba Banji Akintoye, up lgboho oshaa, up koiki media, movement continues thanks.
Iru Yoruba ewo ni sir? I can not go so deep in yoruba if I want to talk to many people, I am considering those who can not understand very deep yoruba, secesa gbo gbogbo ohun ti anso?
Eku atunse sa, eku eto, mo ki yin, eku ise opolo, ( Defibrillator ) je irin ise alagbara ti ama nlo lati da emi pada si ara eniyan ti oba fe pa ipo da ni'le iwosan. Yoruba tife pa ipo da ninu ile iwosan Naijiria ti awon oyibo toju resi, sugbon gbogbo eyin ti Olorun nlo gegebi irin ise yen ni koni jeki oku sinu ile iwosan Naijiria na. Gbogbo wa ni ama dijo gbe asia olominira ti YORUBA NATION na s'oke ni agbara Olorun. Amin.
Yoruba ko si ni a’be ikoso eni kankan. E je ki awon eniyan mo wipe, Yoruba fe yera kuro ninu ajosepo ni ilu Nigeria. Yoruba ti ni ominira ki awon agbenisin oyinbo to’wa ba wa gbe
You only hate the Igbos period and that’s why Fulani will never stop inheriting your land just like they did in Ilorin. Continue the hate on the Igbos last last Fulani will surprise you, because they’ll soon take another Yoruba state. Baba olote ni yin