Тёмный

O ṢẸLẸ, EYI NI BI WỌN ṢE JA ẸRONPILEENI NAIJIRIA GBA NILUU OYINBO, WỌN NI TINUBU BINU RANGBỌNDAN 

Alaroye onlinetv
Подписаться 79 тыс.
Просмотров 26 тыс.
50% 1

What an embarrassment! How battle between Ogun State and a Chinese firm led to the seizure of three Nigeria presidential jets in France.

Опубликовано:

 

12 сен 2024

Поделиться:

Ссылка:

Скачать:

Готовим ссылку...

Добавить в:

Мой плейлист
Посмотреть позже
Комментарии : 70   
@pauloladimeji2514
@pauloladimeji2514 22 дня назад
Kolorun bami Lora emi iwo okunrin to ka iroyin yi, ede Yoruba to yanju gedegede, lofi ka, ode ni ifarabale pelu e, paapa. Eku ise oo, Olorun abami daabo boyin o. Love you so much.
@oluwashinaebenezer6190
@oluwashinaebenezer6190 22 дня назад
Youre too good my bro. Wow Youre too sweet Yoruba language is sweet.
@donekay7976
@donekay7976 22 дня назад
This News man sounds so good mehn 😂🤣
@roselinebolanle9404
@roselinebolanle9404 22 дня назад
More is coming Awon oleee owo gbogbo citizens naa nse basibasu🐎🐎🐎🐎🐎Awon oleeeeee Nigeria leaders oleeeeee
@ogunrindeadebisi
@ogunrindeadebisi 22 дня назад
Daniel gbenga OLEEE NLAAA Oloriburuku BABA Aroo , Gbogbo yin Le MAA shofo .
@aladjimoustaphaiguewassiou9576
@aladjimoustaphaiguewassiou9576 20 дней назад
My brother, ọlọrun a ba mí lọra emi rẹ, ọlọrun ọba kò ni jẹ kí ile isẹ alaroye Jóná, oloriburuku ni gbogbo awọn oloselu Naijiria,, ọlọrun ọba kò sí ní jẹ kí wọn bọ níbẹ,ki gbogbo ayé le mo pe o ni Jibiti ni gbogbo wọn,
@user-lu7pd1qc6t
@user-lu7pd1qc6t 22 дня назад
Oro radarada odidi olori orile de Nigeria ni wan yeye bayi oga oooooooo
@ABDULKARIMSALMAN-d5m
@ABDULKARIMSALMAN-d5m 20 дней назад
❤ Alaroye eku ise takuntakun Adupe ti e je ki eti wa di si Ohun to nlo lawujo wa,Eleyi tun ga o,Oro na si mu eko to po Dani, Oluwa alaanu julo yio bawan yanju re o,
@taiwobello9807
@taiwobello9807 22 дня назад
You're blessed richly
@Adugbo
@Adugbo 22 дня назад
Awon olori buruku, eni boun be
@AdekunleZainab-yt7tk
@AdekunleZainab-yt7tk 20 дней назад
Ile taba fito mo loro gbogbo yin, iri ni yoo wo, awon inu buruku ogun osi, se e ribi tiwa imotara eni nikan yin bawa de, Oba toje tilu roju, oruko re koni parun, eyi toje tilu darun, oruko tie naa koni parun, eyin nihun Olorun ni hum 😎
@akinyeleolatunde1185
@akinyeleolatunde1185 22 дня назад
Alaroye........E ku. Ise oooo
@user-xn6kn6eg6q
@user-xn6kn6eg6q 22 дня назад
Olorun a ba wa yanju Oro yio Amin Egbin ati iwosi nla Alaroye e ku ise opolo o ile ise yin o ni jona o Amin.
@ogunrindeadebisi
@ogunrindeadebisi 22 дня назад
Oloriburuku ni Gbogbo Awon TIO SE Adaari WA ni Nigeria, TINUBU BOLA HAMEED YI NA LOGBE GBEGA DANIEL NA WAA OOO , WAN JO MUGBANA , Oloriburuku ni Wan , TINUBU BOLA HAMEED GANGAN LOBA NIGERIA JE , AWON OLORIBURUKU OLEEE ENIJERE OMO NIAGBARA OLORUN ATI AGBARA YIKUULE ABIAMO , HAAA SERI WAHALAA TIE DASI NIGERIA . OFOO NI GBOGBO YIN OOO NIAGBARA OLORUN LATI ORI ASIWAJU OFO .
@aishahassan6327
@aishahassan6327 22 дня назад
Obasanjo lo gbe Gbenga Daniel wa ni 2003
@sussanahogunbo6681
@sussanahogunbo6681 22 дня назад
BABA ALAROYE ENYIN NA KU OHUN ESISIN TI NJE ELEGBO LOJO TO TI PE NIBAYI ELEGBO NA FE JE ESINSIN LORO BA DI HUN ELEDA GBOGBO OMO NAIJIRIA TI DIDE IJA BAYI A SE GBOGBO ORO NA NI A NWO A O GUNLE LAYO LOLA OLORUN IRE O
@sijisiji8100
@sijisiji8100 22 дня назад
This reminds me of a woman who shouted some year ago 'please just sell Nigeria!!!' Nigeria is already sold!
@agbekeaiyedun7107
@agbekeaiyedun7107 22 дня назад
Awon Oloribuuuuu, Ole gbe Ole gba ,Ofo ni gbogbo yin ma se tomo ni agbara OLORUN,Kill nď divide government.
@adekunlefodilullahmfa7700
@adekunlefodilullahmfa7700 22 дня назад
Alaroye eku ise ooo eku oro Ede Yoruba oni paru ooo❤❤❤
@mariamasie9329
@mariamasie9329 20 дней назад
Ki Olorun bami gbe Sowore le won lori ko ro won si ewon,Revolution now
@imamabdulrasaq401
@imamabdulrasaq401 22 дня назад
Hmmmmm O ga oo Nigeria ra Aeroplane Won si gba Aeroplane Nigeria ni France,,, France yi na si ni Ile Tinubu Ibe ni ile iwosan re Otiyemi
@sakenatafolabi8666
@sakenatafolabi8666 22 дня назад
HMMMMMMMMM NIGERIA HMMMMMMMMM 🤔
@helenadegoke6922
@helenadegoke6922 22 дня назад
Inu abimoku kiidun, inu gbogbo enitoba fiyaje mekunnu koni dun. Rederede nii gbeyin ere osupa rederede nio gbeyin gbogbo eyin ika oloselu Nigeria. Ea kuure. God will use you against each other expose each other and you will not have peace of mind you unfortunate people
@olayinkaagunbiade9116
@olayinkaagunbiade9116 22 дня назад
Amin loruko Jesu
@OluwaDamilare-k5y
@OluwaDamilare-k5y 22 дня назад
Una never see anything 😂😂 Esese bere eti ri kan kan
@mosesbalogun966
@mosesbalogun966 22 дня назад
Amin iya lomaajewon Di ojo Alewon.
@Rebecca76001
@Rebecca76001 21 день назад
No wonder Our 68billion naira was ebezelled by Amosun and Abiodun is still battling to pay back though they are all the same,
@ismailaademola3100
@ismailaademola3100 22 дня назад
Nigeria jagajaga
@Omoba65
@Omoba65 22 дня назад
Kaabo. Bi o tile je wipe kii se iroyin Ayo. Bi oniroyin yii se gbe kale dun pupo. Ohun re ko mi baje 🙏
@adewaleadeniran2534
@adewaleadeniran2534 12 дней назад
Akagbadu ni iroyin yi oooo
@Omoayo7066
@Omoayo7066 22 дня назад
Gbenga Daniel Ole, e wo bo sesi imu.... Esan sese bere sinu ke lori eyin Ojelu ijoba ilu Nigeria Ole. 419.
@user-db6zg1nf5d
@user-db6zg1nf5d 22 дня назад
AMOSUN RADARADA ENIYAN ‼️TI O SO IYAWO RE DI BENBE NABIU, OUN NA MARI EWON E LAI PE
@ogunsegunezequieldamilare5869
@ogunsegunezequieldamilare5869 21 день назад
😂 Naija my country
@paulmark7478
@paulmark7478 16 дней назад
Sold nation
@OmoolaTv01
@OmoolaTv01 21 день назад
I hope we won't go back to slavery 😭
@AmokeojaOlawale-ko6lk
@AmokeojaOlawale-ko6lk 20 дней назад
Ejo awon agba bo won ni ika Toba SE gege ni won magbe o kiwon gbe amosu,igbegba, Daniel,ati dapo abiodun kiwon loje oje won ni ohun Toba je iku ni Toba si je won ma gbe gbogbo nkan iniwon naa ni kiwon SA da ikan fun won nibee o
@KazeemKareem-xn8tr
@KazeemKareem-xn8tr 22 дня назад
Well done sir
@olawuyiadejare931
@olawuyiadejare931 17 дней назад
Iroyin yii kun osi yeni yeke yeke
@abiheart5461
@abiheart5461 22 дня назад
Ija ti awon ole yi ja no fi ko ba ilu ogun
@akinsolajoseph5391
@akinsolajoseph5391 22 дня назад
😅😅😅😅😮😂😂😂this man is very sound.. àwọn ìjọba okunkun 😅😅😅😅😅 sè ẹrí aiye yin lò dé 😅😅😅😅
@olayodeayomikunoluwatimile6762
@olayodeayomikunoluwatimile6762 13 дней назад
Wahala 😂😂😂
@saheedadewale5901
@saheedadewale5901 20 дней назад
Oda be
@user-np9hs1tn8w
@user-np9hs1tn8w 22 дня назад
That's lack of continuities government.
@tosintosin-xq6cr
@tosintosin-xq6cr 21 день назад
😂😂😂😂 😅😅😅
@adetounolorundami5257
@adetounolorundami5257 22 дня назад
iwa ika ati iwa ode ni sha
@abiheart5461
@abiheart5461 22 дня назад
Awon oba yee je miji
@adeyanjutemitope4051
@adeyanjutemitope4051 21 день назад
Oro Nigeria yi koye awon oloriwa gan mo
@damilolajoseph5838
@damilolajoseph5838 22 дня назад
Bawo ni baba se fe pada sile
@Omoayo7066
@Omoayo7066 22 дня назад
🙈 ilu Nigeria oju timi fun eyin Ole. 419. Ijoba wa pata! 🙈
@mariamasie9329
@mariamasie9329 20 дней назад
Ki won gbe ese le Tinubu. Awon akotileta arungun
@Babatope-up4iu
@Babatope-up4iu 22 дня назад
Oponu lo poju ninu awon oloselu wa
@abiheart5461
@abiheart5461 22 дня назад
GBOGBO YIN NI OLORUN MA DA LEJO NI TO RI BESE BA ILU NIGERIA JE TI EFI OWO SOWOPO PELU ARAYIN KI ILU LE DUN IMO TARA ENI NIKAN LOBA GBOYIN JA
@RazeedAyinki
@RazeedAyinki 22 дня назад
Oloriburuku ni gbogbo won
@ModupeEsho
@ModupeEsho 22 дня назад
Hmmmmm
@rontibello7796
@rontibello7796 22 дня назад
Eku ise opolo oluwa aduro ti yin
@Dr.Oduwole
@Dr.Oduwole 22 дня назад
Naijiriya je gbese ,ijoba Ogun lon San owo ,meanwhile sanwo olu dey for Lagos
@KEHINDEGBAKINOLA-xp4rw
@KEHINDEGBAKINOLA-xp4rw 22 дня назад
Otan 😅😅otilo
@kehindebellosikirubello989
@kehindebellosikirubello989 22 дня назад
Awon oloriburuku Dede awon ojelu dede
@abiheart5461
@abiheart5461 22 дня назад
Awon lori buruku meji
@RolynRolyn
@RolynRolyn 22 дня назад
So, Are you guys surprised for three Nigerian aircrafts that was ceased in Paris? Just dey play. Chinese has already buyout Nigeria for so long. In another 5 decades we’ll be speaking Chinese.
@sherifatagbabiaka8284
@sherifatagbabiaka8284 21 день назад
Won tie ti ta ile Yoruba tan awon ole.idajo olorun ake lori yin tomotomo 🙏🏼🥲
@abiheart5461
@abiheart5461 22 дня назад
AWON OLODO GBOGBO
@jomoniwaoronla3873
@jomoniwaoronla3873 22 дня назад
😂
@gabsonoladejo4100
@gabsonoladejo4100 22 дня назад
Iku ise takuntakun
@SaheedAdekunleAdedeji
@SaheedAdekunleAdedeji 22 дня назад
😂
Далее
Sowunmi Queries NNPCL Over $6bn Debt To Oil Marketers
21:39