Shebi OBJ kalokalo lo so wipe, gbese to wa ni ile , awon Iran ton bo leyin lo ma san owo naa,hmmm OBJ ba aye iran wa je lati odun 1999,kaa pin jeje ki onikaluku gba ile baba re lo,ona eburu lafi da orileide naijiria si le, Yoruba ronuuu!
Oloriburuku ni dangbote apanian ni emefiole. Ori omode, ori agba lonse idajo won koni ye won koni dara fun won ati gbogbo awon isongbe alabasisepo won, won oni nisinmi rededrede ni yo gbeyin gbogbo won. Nobody got dangote in to trouble his wickedness and long trouth that got the fool into trouble. They've just started God will expose all of them.
Its high time Nigerian government stops Dangote from monopolising sugar, cement, and fuel markets and opening the Nigerian market for perfect competition, even the world bank and IMF commented about no fair competition on Nigerian markets in their reports
olorun ko da eni ti kole mun olorun a se idajo fun gbogbo won, idajo olorun ju ti omo eniyon lo ema wo iron ikon ti olorun ma se fun gbogbo won pata loruko jesu kristi oluwawa Amin
Either we divide Nigeria or not, hope is not lost yet, let us be faithful and honest with all we are doing. All the step we are taking have reward. No matter how richest you are in this world. You have been destined to died once. i want to ask a question that we should all must answer. How many people that have died and bury along with his property?.
Mo ro pe idi niyen ti Baba Obasanjo, Bishop Oyedepo, Pastor Paul Enenche ati awon olowo bi Dangote ko se gba fun President Tinubu sugbon won se alatilehin fun Obi, lati gbe ihinrere tara won gaa. Ole barawo ni awon emofiole, Dangote, ati awon ti mo daruko yii. Oba to ga ju gbo aiye lo a se idajo won loruko jesu Oluwa wa, nitoripe won ti ba ile oko owo Nigeria je pupopupo.
E fi dangote si le won fi dangote se olori. Obasojo Babagida Abudusalam awon ti won ni dangote ni yin.e wo ibi ti won ba Nigeria je de Olorun lo ma se idajo gbogbo yin eni ti ale mu Olorun la fa yin le lowo
It was ABACHA that gave Dangote and his late son,the sole license to be importing sugar and other things.We should stop hanging everything on the neck of Obasanjo, it's very unfair.