Eku eto olotu. Sugbon, you could have let baba skip where he had to described how incision with voice commands are used. Gbogbo aso ko la sa loorun. Once you let the enemy within Yoruba land aware, they will go and look for the antidotes to subdue the effect of the voice commands.
Eyin Oniroyin Iwonba Lo Ye Ki E Ma Se Iwadi Ba Awon Asiri... Gbogbo Bi Iwo Naa Ti Nbere Asiri Yii, Gbogbo Asiri To Wa Lara Re Ti N'baje.. E Sora Fun Awon Ibere Yin..{Olorun Oba Eleda Ohun Gbogbo Lo Ma Nfi Asiri Ikoko Han..