Baba mi ro mi lagabara ti mofi nko awon eye aje| Asiri agbara ti mofi npa ekun ati awon opolopo Eran abami yi wa pelu mi lako bi Ibon|.
wonyi ni awon Oro ti Baba Aluwo, Olori gbogbo awon Ode Ipinle Kwara, ti won tun je Baba Isale fun awon egbe Oduduwa Peoples Congress{OPC} so.
25 мар 2023