Omo ikirun ni mi omo ile Eesa agunbe onile obi egbon baba mi ni Eesa to wa Lori oye bayi, baba iya mi sini ogbontarigi ode Lasisi Olakangudu ki ile ma gberi fun baba iya mi ati baba babami Eesa Adeleke ano awon okunrin takun takun niyen. E shey atokun ti e de ile babami. E bere odofin ode ikirun baba logoja ki e shey iwadi de odo wan naa.
Bi ao ti e gbo ede ti efi nbawa soro, ani Igbagbo pe kiise pe e koro oju si fidio yí. Boti wu kori, Adupe lowo yín;Àdúrà wa ni wipe, Eledua yo lanan Irẹ fun yin, onan Ayo yo la fún yin
After God (Oludumare) are the Orishas like Ogun. Arabic and Jewish Allah and Jehovah are equivalents of our African Orishas like Ogun and Orunmila, not superior.
En fi ogun no ra yin is illiteracy if you ask me. This is why most yoruba are scared to do Isese, but go join Muslim or Christian religion. Stop scary people by using ogun to test each other