Eseun baba Olorun ama fun yin se o lase edumare. Ejowo baba wa ibere mi se aro ni ama la etu yi ni abi ale atipe igbawo si igbawo ni lilo ise yi Bakan na ose re se ale ni wiwe re abi aro. Ema binu baba eseun sir
Yio darafunyin baba sugbon ejowo ati gbogbo enito comment bamo odu ifa ti baba pe yi kanfunmi, momo ejiogbe sugbon mio mo oguda abi ohun ni ogundagbede ni sa. Adupe sa
The way person Wil use it... After the incantation can I use soap and vigu milk to use it same time or it most be one.. And is it at once person Wil use everything