His just like me. I'm so happy he stand for ibile. I wish to do this but I can't but I'm much happy he did it and stand for Yoruba culture. Eledumare go bless u and stand with by u
Honestly, you are always on point bro.. I am a Nigerian living in Dubai. I can testify to it that Nigeria Muslims are something else which I don't understand the way they are practicing the Islam 🤷🤷🤷🤷
You are the best Tani Olohun. You speak well. How can these impostors ascribe the ingenuity and work of our ancestors to other people - these people are so desperate and want to install a fake order on the people. Thanks for your work Tani Olohun and may the ancestors continue to guide you.
Gbogbo igba ti mo ba ti n 18:01 wo eto idunnu lati enu Tani Olohun, nise lo ma n dabi wipe, ki o ma tan ni. Omo Yoruba gidi yato si awon Omo Ale jatijati elesin alakatakiti ñi Tani Olohun; awon Onile yo ma fun e se. Ase n'tedumare! Isese ti n gba aye lo bayi loju awon Omo Ale Yoruba. You're doing a good job with the grace of Eledumare! Isese laagba. Ire o!
@@sakasaheed7110 adura Kan ti eyin akidanidani alagidi muslim ma ngba na niyen. Iwo to ti pare maye because ati jeun di wahala fun e. Iya nla nje e. Nincompoop!
I Don laugh die. Defensive war. Muhammed was defending all the attacks, till enemies got tired.. Then later they greet themselves good bye to continue the war another day... Ooh boy!
@@KazeemAhmed-dy5vh I no blame you at all, ignorance has been weaponized in Ilorin. Majority of you has been hypnotized ,manipulated and brainwashed badly by Awon afa olosuka iya lori. I just pity you guys what Industrial , human or capital development has religion brought to Ilorin ? Eyin alabosi gbogbo wonyi . Nigeria is a secular state not Islamic or Boko haram country…Ilorin people should let christians and onisese practice their religions. God has no religion.
@@tyade7969 can you see how fool you're where and when did you see Ilorin people disturbing the Christians and for your information who has been brainwashed between you and I you that believe in the useless myth that your oduduwa descended from the sky with chain,you that believed in God(Allah)creatures rather than God(Allah)himself Alhamdullalahi I believed in oneness of God(Allah)not his creatures e.g Osun,Obatala,Masquerade,IFA and orunmila that's the creatures that you worship shiorrr
DONT ALL THESE ALFA MABY OF THEM WILL GO TO HELL,MY BROTHER YOU ARE DOING GREAT,IN YORUBA LAND EVERYONE IS FREE TO WORSHIP ANYTHING YOU FEEL LIKE DOING
Sorry, Taniolorun. Se ifa tabi awon irumole naa lo so bi awon eranko igbe se maa nlo ewe ati egbo? Se awon naa ni won so fun awon onimo ijinle (Scientists) bi won ti nlo ewe ati egbo fun isegun aye ode oni ? Otito ti o wa nibe ni pe Olorun Eleda ti da awa eniyan re ati awon eranko paapaa pelu igboungbe (urge/requisition) lati ni imo nipa iwulo ohungbogbo ti o yi won ka fun anfaani won. Lati inu ogba edeni ni Olorun ti fa akoso ati iwulo gbogbo iseda yoku le eniyan l'owo. Se ifa naa lo so fun omo tuntun lati maa wa omu iya re, tabi fun eranko lati maa ni asepo lati bimo ? Se ifa/irumole naa ni o so fun awa ati eranko gbogbo lati maa mu omi, etc. Gbogbo awon ti e pe ni orisa wonyi je eniyan ti awon na ba ewe, egbo ati iseda yoku laye, ti won si se imulo won gegebii imo ati oye won ti mo nigba naa. Bi awa eniyan se nla kaka lati mo sii ni imo ati oye nipa iwulo ohun gbogbo ti Eleda fun wa yoo maa po sii. Ewe ati egbo wonyi naa yoo sise laisi ogede/irubo/pipe oruko orisa kankan nitoripe Olorun ni o ti fi agbara wonyi sinu won fun iwulo wa. Nitori naa, Eleda wa ni o ye fun wa lati gboriyin fun. Abuku esin musulumi ti o ga julo ni fifi ipa, iro ati iwa jagidijagan fe pa gbogbo esin iyokun re laye ki awon nikan lee je gaba lori gbogbo eda. Eleyi buru jai, ko si lee je lati odo Olorun Eleda wa nitori ko fi ije omo eniyan han. Iwa naa jo ti eranko alainiye ninu. E jeki gbogbo wa maa gbe po ni irepo ati ifowo-we-owo. E jeki gbogbo wa doju ija ko iwa ibi, iyannije ati iwa ika si elomiran. Alaafia fun gbogbo wa.
I still dont understand, God in the Old testament wanted sacrifices and God in new testament didn't want it Are they telling us God also changes his mind.😂😂😂😂
Neither the pharisees nor the gentile and Ceasars in between I am not not religious I appreciate tradition then the some preaching of Jesus most especially love
Eru omo eran Iran Kiran.. your useless book quran is not against it but you guys are hating the elebò people after they have shown you guys ways about isèse.. oloriburuku ni gbogbo yin patapata omo ale eru larubawa eru fulanis oshi omo ale lasan lasan lasan
@@oluwafemijohnmiracle9877. O seun pupo omo Yoruba atata pelu lakaiye Oro ti o jaade lenu e. E fi awon alaimokan amukunmeko alainironu alakatakiti esin sile tiko si lakaiye kankan funwon
😮😮. Opurọ ayé àtọ̀run làwọn èèyàn ìkà alfa ìsọnu wọ̀nyí láwùjọ wa. They're confused 😕 bunch of deceptive fools. Àwọn illiterate gbogbo. They all eat herbs & vegetables . God made them for our own use . Genesis 1 :29 - 31 says "And God said, “See, I have given you every herb that yields seed which is on the face of all the earth, and every tree whose fruit yields seed; to you it shall be for food".. Olúwa ṣeun fún àwa ẹ̀dá láyé gaan ni nítorítí ÀÁNÚ rẹ dúró títí láéláé nínú ayé wa tọmọtọmọ tẹbí tará títí láéláé ÀMÍN Láṣẹ Èdùmàrè