Oloriburu ni gbogbo yin iru e a kan yin lagbara olorun you African tv ole ni e orun ma da jo fun e, ole oloriburu ni Larry African ti be ya Jiya ise owo e, lagbara olorun amin oooole Larry
Gboogbo yin pata OLORIKORI niyin oo, sabiayo LEYIN YII shaa, gboogbo ohun to sele si baba MOHBAD lo maa de ba gboogbo nyin, ENYIN nfi iku omo yo enikan , OLORUN maa mun nyin oo, se baba wa nibe NIGBATI driver gbe wumi ati moh lo si show,se baba wa nibe NIGBATI Mohbad ku,se baba lo ni ki nwon o ma gba oku Mohbad ni mortuary,se wumi ko lo gba doctor report dani ,ki darosha o to lo embalm moh nile ,ki wumi to nb ki baba lo ro oku ,enyin nuun OLORUN NUUN, GBOGBO ENYIN Okunrin ALABOSI TE nrerin yen niru e maa kan oo, omo ENIA ku ,e wa nmock e ,haa eo beru OLORUN