Congratulations oniba ekun kabiyes nd oloris eku orire na ati barakat nd olatunji ekoni foju sunkun awon mejeji won yio bi ako won yio bi abo won a ri arisiki se aye awon omo mejeji yi won koni kabamo laiye amin olorun yio mu won de ile ileri ni ase olorun nkon rere rereni ama maba arawa se o iku ojiji koni ya nile enikankan wa amin emi kabiyesi na yio gun won yio pe laye won yio fi erigi je obi barakallahu fii kum amin kunfayakun amin