Mr fajugba ise dada ni e se Amo e fi ogbon se gbogbo oju awon agbagba wa ti e gbe si ita yin.se e mo pe ota po ewo owun to lo ni Nigeria Oluwa a wa pelu yin please
💯 Agree!!! So they don't use our own knowledge against us! E sora fun awon Oyinbo . Ole ni awon alawo fun fun. Won ti bere si ko ede Yoruba lati ko ifa, ati asiri agbara ibile Yoruba. E ma gba won laye o!!!
@@omokaroojiire ❤💯 I SWEAR BRUS. THIS IS WHY WE AS YORUBA AS A WHOLE NEEDS TO COME TOGETHER AND DRAW A LINE. THEY ARE DOING EXACTLY THAT TO ENTER AND ACQUIRE HIDEN KNOWLEDGE LIKE AFERI, OKIGBE, AYETA ETC. NA YORUBA GE PHONE AND LAPTOP IDEA. IFA IS GOOGLE IN OUR 21CENTURY
@@omokaroojiire This is why we need to stop exposing our secrets. See ilorin, alfas knows and have same secrets our babalawo gives them for money after collecting from hunters. There's a video of elebuibon of oshogbo, and he said how he's been translating our isese secrets to oyinbo so they can further study it. We need a limit to what we give out to people. History showed after w*r btw Africans and oyinbos, due to ogun baba wa, oyinbos couldn't win the battle, now, they're studying what we used to win that f*ght
Baba wa adupe lowo yin,sugbon eranti pe awon kan wa ti won kise omo Yoruba,ti won si je ota Yoruba, gbogbo nkan ti e nwi yi se awon ota wa o ni fi ma doju koni?
Thank you for this interview, Mr Fasugba, you're doing a wonderful job. This is very interesting and informative. There are a lot to learn from this Baba. I hope, he will have either a CD, to record his knowledge for his family to use in future. Thanks.
Hello Dr OLAKUNLE FASUGBA. GOD Almighty Father will protect you and bless your family and your Generation thanks I Love your PROGRAM too much. Very sensebIe, And his good to be Listening to all the times..
se Yoruba ni asiri konkon bayi. mi o le ro be ati pe ti oba je be ni. bawo ni awon aginigbe wole was ji oba Meri gbe won pa megi ni be. won tun gi awon agbe gbelo won tun ba gbogbo awon obirin wa sun ni ikonkon. gbogbo ile Yoruba patapata ni won wo ti ikonkon ko de sele. pelu. A.K.47. lowo. ti ogun baba ye badaloju ki odoju ijako awon ajini gbe Kari iKon to ma sele
Gbogbo tribe na ni won ni agbara tiwon, eleri ki won matu asiri agbara won ni ori afefe, sugbon Yoruba oro won koye eniyan rara tiwon ko tie ni asiri kankan, igbati gbogbo iru agbara yiwa lowo yin, kin ni ewa nwo ti awon Fulani fife pawa tan ni ile Yoruba ti ekori nkankan se si yen
Blessing the last one which is part 3 is selling for 10k plus 5k for original honey making everything 15k and you seen him live and direct at his office in egbeda Lagos
lol this interviewer is really Omo Odo Agba, he knows most of what the baba is talking about already especially when he talked about the snake bite but just reserved without interfering so the baba can talk
With respect, I disagree that India 🇮🇳 don't play sports. Football ⚽️, cricket 🏏 and some Olympic sports. India 🇮🇳 have successful record in the sport, however football is a well known sport that requires skills and specific speed of which India lacks enough of such genetically compared to African race.
He knows more about traditional medicine but he cannot deliver himself. He knows about making rituals money but it doesn't do it for himself. He is just making mouth with his sugar coated mouth.
Ẹ kú ọgbọ́n inú, bàbá. Inúu wá dùn,ara wa gágá pẹ̀lú. Ẹ kú ìmọ̀ lórí nnkan abáláyé orílẹ̀-èdè Yorùbá. Ìmọ̀ràn: Kí YORÙBÁ GIDItv jọ̀wọ́ gbìyànjú láti máa dáàbò bo àwọn àṣírí tó wá nínú ìwádí rẹ̀ gbogbo ní torí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọ̀táa ọmọ ÒDUÀ. Onímọ̀ nínú oògùn àbáláyé ti YORÙBÁ ni mí--Traditional Yorùbá Medical Practitioner, Ph.D.