Тёмный

Àwọn ẹ̀dá tó ń gbé inú sánmàn àti àwọn awẹ́ ojú-òfuurufú 

Science in Yoruba
Подписаться 1,8 тыс.
Просмотров 3 тыс.
50% 1

Àwọn ẹ̀dá tó ń gbé inú sánmàn àti àwọn awẹ́ ojú-òfuurufú (Creatures living in the sky and layers of the atmosphere)

Опубликовано:

 

30 сен 2024

Поделиться:

Ссылка:

Скачать:

Готовим ссылку...

Добавить в:

Мой плейлист
Посмотреть позже
Комментарии : 25   
@abioyeadeniyi6131
@abioyeadeniyi6131 8 месяцев назад
Eni ti o se akoso gbalaja ofurufu ni a n pe ni Adeda, Aseda Eledumare, Olorun
@tolulopesoyemi2914
@tolulopesoyemi2914 Год назад
Hmmm... omo oduduwa rere. Olorun a tunbo ma fi kun oye yin
@abioyeadeniyi6131
@abioyeadeniyi6131 8 месяцев назад
Inu mi dun si idanileko yii. More wisdom
@sherimango3868
@sherimango3868 Месяц назад
Ẹ ṣe púpọ̀ 🎉❤
@mubahcreativity8127
@mubahcreativity8127 Год назад
Eku ise opolo sir Ibeere mi ni pe Boba sepe obiiri alawe nibe ni osoonu (ozone) wa, se iyen ni pe eni to be rekoja awe Yi yoo ma fara kaasa awon ifewele (radiation) Orun? Boba ribe awon onimo ijinle to n rekoja re n ko? Eseun maama reti esi yin
@adedejimutiat3220
@adedejimutiat3220 10 месяцев назад
Bravo grate research
@adesolaoladelerotimi7305
@adesolaoladelerotimi7305 Год назад
E Ku ise opolo, OLORUN OBA yoo ma fun yin ni imo si.....e jowo e maa ba wa gbinyanju lati ma so awon Nos. Wonyen ni Ede geesi, ki o le ma ye wa sii. E se pupo
@scienceinyoruba
@scienceinyoruba Год назад
Ẹ ṣeun lọpọlọpọ. A máa ń kọ wọ́n sí ojú fánrán. A o tun gbìnyánjú láti jẹ ki wọn o máa pẹ sì lójú fánrán. A dupẹ fún àbọ̀ (feedback) yí.
@ahmedsuleiman1130
@ahmedsuleiman1130 Год назад
E sounds pupo fun imole yi.
@olalekanoluwole7011
@olalekanoluwole7011 Год назад
God said it in Alquran that we made sky a protective shield for you
@scienceinyoruba
@scienceinyoruba Год назад
Ẹ ṣeun o
@oladimejiakorede1658
@oladimejiakorede1658 Год назад
Thank u very much more wisdom and knowledge
@scienceinyoruba
@scienceinyoruba Год назад
Àmín o. Ẹ ṣeun gan-an
@ainaadeniyi8470
@ainaadeniyi8470 Год назад
OPOLO YIN O NI DARU ESE PUPO FUN IMO IJINLE TI EFIN YE WA ALLAH ONI JE KI OPOLOYIN DARU O!
@scienceinyoruba
@scienceinyoruba Год назад
Àmín o. Ẹ ṣeun lọpọlọpọ
@emmanueladekunle2772
@emmanueladekunle2772 Год назад
Great work! This is cool
@scienceinyoruba
@scienceinyoruba Год назад
Ẹ ṣeun lọpọlọpọ
@adenolasegun952
@adenolasegun952 Год назад
Thanks for sharing
@scienceinyoruba
@scienceinyoruba Год назад
A dúpẹ́ o
@michaelogunleye6863
@michaelogunleye6863 Год назад
Wooow well done sir
@scienceinyoruba
@scienceinyoruba Год назад
Ẹ ṣeun gan-an
@sundayayanda4318
@sundayayanda4318 Год назад
God bless you.
@scienceinyoruba
@scienceinyoruba Год назад
Àmín o. Ẹ ṣeun
@alomajaadebimpe3416
@alomajaadebimpe3416 Год назад
E ku ise naa
@scienceinyoruba
@scienceinyoruba Год назад
Ẹ ṣeun gan-an
Далее
ТАРАКАН
00:38
Просмотров 1,2 млн
DAXSHAT!!! Avaz Oxun sahnada yeg'lab yubordi
10:46
Просмотров 449 тыс.
11. Byzantium - Last of the Romans
3:27:31
Просмотров 4,7 млн
ТАРАКАН
00:38
Просмотров 1,2 млн