Тёмный

o ya, ẹ jẹ ki a jọ lọ wo ibi ti ojo ti n wa lati inu sanma 

Science in Yoruba
Подписаться 1,8 тыс.
Просмотров 1,4 тыс.
50% 1

o ya, ẹ jẹ ki a jọ lọ wo ibi ti ojo ti n wa lati inu sanma (Now let's go together to locate the spot in the sky where the rain comes from)

Опубликовано:

 

30 сен 2024

Поделиться:

Ссылка:

Скачать:

Готовим ссылку...

Добавить в:

Мой плейлист
Посмотреть позже
Комментарии : 20   
@ahmedsuleiman1130
@ahmedsuleiman1130 Год назад
Ọlọ́run a ma fún yín ni àgbàrá àti oye lati má tan imọlẹ lórí òun ti ko ye wa. Ẹ ṣeun pupọ.
@mohammedadabanija7008
@mohammedadabanija7008 Год назад
E seun gaan ni fún àwọn fónrán ti é fin dáwà lẹkọ, ọlọhun koni ba ọpọlọ yin jẹ o. 1-E jọwọ mofe beere wipe se " se baalu le fo koja obiri alayipada mararun? 2- Se ori earth🌎 naa ni e wà, Abi e ti wa ni agbegbe awọn planet ? 3- se leyin awon obiri alayipada mararun ni sanmọ kíni wa ni? 4- Se science fi múlẹ wipe Sanmọ méje àti ilé méje wá gẹgẹ bí iṣẹ wa ninu Al-kurani alaponle? E Seun pupo 🙏
@astech1607
@astech1607 Год назад
IKÚ ISE TAKUN TAKUN, Mo ní Ìbéèrè ti mo fe bi yii, gege bi ikan ti e so eni kurukuru ni ma ro ojo ti o túmọ̀ sí pé omi ni kurukuru, Ìbéèrè àkọ́kọ́ ni pé bawo ni ose duro si oju ọrun ti ko si da wa le and se Gravitational force ko se ise fun ni? 2 bawo ni balu se la inu re ni aaifi ara kan omi?
@oladejilatif8468
@oladejilatif8468 Год назад
Ise olohun awa maridi, olohun a wa pelu yin sir. Safe journey
@abdwasiiaminatadewunmi1025
@abdwasiiaminatadewunmi1025 Год назад
Eku ose opolo
@waheedolawale8827
@waheedolawale8827 Год назад
Ejowo ebawa tanmole si awon abemi (living things ) toma njabo lasiko ojo awon bii eja, ekolo, ati bee bee lo nigba tieni kurukuru kole gba nkankan duro nibo wani awon eja tinjabo lasiko ojo
@adenolasegun952
@adenolasegun952 Год назад
E SE pupo fun awon eko yi
@TaofikatOlawale
@TaofikatOlawale Год назад
Wow! Eleyi wu ni Lori o! Oku ise ara, Olohun Oba adeda! E seun fun faran yii, Olootu. Koni baje fun yin Lola Allah!
@scienceinyoruba
@scienceinyoruba Год назад
Àmín o. Ẹ ṣeun lọpọlọpọ fun àtìlẹ́yin yín ❤️❤️❤️
@alexliberty1559
@alexliberty1559 Год назад
Olorun a tunbo maa bukun làákàyè yin o
@scienceinyoruba
@scienceinyoruba Год назад
Amin o. Ẹ ṣeun o!
@ainaadeniyi8470
@ainaadeniyi8470 Год назад
KO NI RÈ YIN BA KAN NA KONIRÈ OPOLO YIN
@scienceinyoruba
@scienceinyoruba Год назад
Amin o. Ẹ ṣeun o.
@ainaadeniyi8470
@ainaadeniyi8470 Год назад
KO NI RÈ YIN BA KAN NA KONIRÈ OPOLO YIN
@scienceinyoruba
@scienceinyoruba Год назад
Amin o. Ẹ ṣeun gan-an!
@iam_realabiodun
@iam_realabiodun Год назад
Ẹkú iṣẹ takuntakun
@scienceinyoruba
@scienceinyoruba Год назад
Ẹ ṣeun gan-an ni!
@iyaadura9588
@iyaadura9588 Год назад
If cloud is kurukuru, what is fog?
@scienceinyoruba
@scienceinyoruba Год назад
Òwúsúwusù ni. Ẹ ṣeun gan-an
@iyaadura9588
@iyaadura9588 Год назад
@@scienceinyoruba Thank you very much for the knowledge
Далее
Ijiroro Lori Idajo Awon Olopa Ti Ilu Ilorin
1:22:13
Просмотров 4,3 тыс.
Шоколадная девочка
00:23
Просмотров 303 тыс.
Трудности СГОРЕВШЕЙ BMW M4!
49:41
Просмотров 1,7 млн
Alaafin of Oyo Speaking on Chief Obafemi Awolowo
25:46
Просмотров 136 тыс.
Ayé Júpítà
3:24
Просмотров 533