Ara nkan ti a nwi leleyi o. Awon agba Yoruba pe ipade si aafin Oonirisa, ede geesi ni won nso. Eyin baba wonyi gan le ko ba wa. Eyin le nta wa fun awon amunileru. Emi o le bu awon musulumi ti won npa itankitan nipa wa mo. Niwon igba ti eyin agba Yoruba paapa ko se aponle ede abinibi wa. Se awon Fulani tabi Igbo le pe ipade laarin ara won ki won ma so ede amunileru? Ibi ti e ba ba wa de, Iran ko ni gbagbe gbogbo yin.😭😭😭 Kilode ti e ko ki kabiyesi ni ede geesi ka kuku mo wipe a ti sonu patapata?
Misplaced priority elders, Awolowo KO RI Ile filele lomo LOWO. ADUPE FUN MOA VOICE OF OMINIRA YOURBA NATION SOVEREIGNTY 2022. DEMOCRATIC REPUBLIC OF THE YORUBA DRY/IYP AS STAND . EYIN BABA EDIDE
The Afenifere should make Yoruba language very compulsory. The opening address was read in English language. I am happy that the Ooni himself addressed the congregation in Yoruba language. Let us learn to enhance our language to the international level. Eya wa ko ni rehin lailai, amin.
I so much love kabiesi Adeyeye Ogunwusi Ojaja from the bottom of my heart. He's very respectful and accommodative and çool headed, intelligent and hear listener. May he says be long ni agbara Eledumare. Amin aseee. Ogbo Atoo.
Yoruba Nation now now ASAP. No going back. We say no to re amalgamation. Where were you so called elders when the fulanis were kpaing jinigbe and collecting Ransome. Please be sincere in your demands. We your children are not happy with you people as our leaders. Yoruba Nation now now ASAP. No going back. God bless Yoruba Nation. Oduduwa a gbe wa ko nii gbe odale. Olorun a wa pelu gbogbo wa. Aamin.
Yoruba Afenifere meeting with Ooni conducted in Colonial Language is a joke and very sad indeed 😮 Yoruba Language should be the official Language in Yoruba Lands!!! I'm very proud of Ooni for addressing in Yoruba Language Ade a pe Lori Baba wa❤
Abi o ! Ask me o. Oko eru ti Oyinbo fi won si lo fa, abi tani ko gbo Yoruba laarin won ? Awon eyaa miran ko ni joko ipade nipa Ile won ki won so ede miran afi ede abinibi won.
WHO IS ANOTHER TRIBE IN AFENIFERE THAT COMPULSORY THEM TO SPEAK ENGLISH INSTEAD OF PURE YORUBA THAT IS ONE THING SPECIAL ABOUT HAUSA THEIR LANGUAGE FIRST BUT YORUBA LANGUAGE ALWAYS SECOND
Truly President Tinubu is one of us, his maximum time on his tenure is 8yrs, whatever his achievement during his tenure, what happens after he lives, will we not go back to old life. All the Obas n babas here, support Yoruba nation n let's claim our land n let our children, youth n adult live a good life sirs. Yoruba nation, no going back.
I appreciate the Ooni very well for addressing the Afenifere in Yoruba language. Thank you Kabiesi. Again, the issue of Yoruba sovereignty should always be paramount in your heart. As Omoluabi, we cannot be co-existent with the criminals.
Kilo de nitori Olorun ti won ko le so YORUBA bayi ,haaa eleyi ma sun mi bayi ooo,nigba te wa laarin Yoruba fun ijiroro laarin ara yin ti ko si elede miran nibe,haa,e jo e je ka gbe ede wa laruge nitori Olorun
Awon ti o pe ara ni afenifere won ki se afenifere , afenifebi awa omo Yoruba ni won, ti won ba je afenifere o ye ki won ba wa fe ohun ti a fe orile ede wa Yoruba Nation ni awa fe. Yoruba Nation no going back.
WONTIRIEYINOBALOJE TIKOBASIYE WANIKI GBOGBO YILOSI ODO ELEGUNSI ATI OBA IIFE SE EGBE ELEGUNSINIYI NITORIPE TINUBULOFIJEOYE OFEMAFIYINWOLELOJUE KISE IFE NIOYEKIELONI TIEBALO EPELOMAPAYIN NIGBATI AWON FULANI.PA AWON OBA KOSEMEET😂😂
Tito bi olohun à ba se bi awon baba Awolowo se se re abi bi pa Bola ige se se re haaa ki wa lode tii eyin wan yii se bayi esi beru olohun eberu ojo atisun sebi ipade Yoruba le pe kii wan lode tii eso varnaqul haaa o .esi pe ara yin ni Agbe Afenifere haaa haaa ebe ojo ati sun ooo ke berun ojo ola ooo Etun ile odua se eje kaa gbe Asa wa larunge
Esehun pupo Baba wa Ooni risa keepe Baba gbogbo Oba Ile Yoruba 🙇🏻🙇🏻♀️ Olohun atunbo ma se alekun ogbon yin. Ejo wo Baba Ooni risa Yoruba Nation la fe ko si ma pe, ao ni ku sajo, ao si niku sona bi eefin ni ase Edumare!🌈🤍
Eyin baba wa. E o pe fun wa o. A o si maa ri yin ba. E jowo e maa bawa so ede yoruba ni awon ipejopo yin. Nitori ede wa ni ogo wa. E jowo eyin baba wa e dari ji mi ti mo ba yaju si yin. Idobale ni mo wa. Mi o too yaju s'agba rara o
A ki eyin baba ku ise awon alale a tun agbara yin se ,A ro yin ki e bawa soro ni ede wa kii se ede ayalo tabi akonileru to sun soko idaduro ti e n so yin oo Awon oba yoruba ni e n ba soro ko si yibo /hausa lariin awon oba wonyi ati awon Afeni fere ,e so ede yoruba ,Egbe ede yin laruge kogo koro yii ko ni ilosiwaju Yoruba e se
I think Afenifere should be representing All Yoruba in kwara and kogi state of Nigeria otherwise they would be creating opposition from within Yoruba people.
Eyin agbaagba wa, e pe aro ati odofin inu yin. Ni ojo miran ti e ba fe se ipade yoruba awa omo yoruba ataata ko ni fe si lati maa gbo ede ayalo rara, e se atunse si I o
Eyin Agbalagba ole ile yoruba odale ni gbogbo yin lati tori president to fi de isale ole ni yin Atubotan bo lori gbogbo yin Olorun ko ni fun se ni Agbara ti Olorun Oba ami o eyin o ni jekuje eyin Ojelu eyin e nki oselu Ojelu ni yin
Eo tun le so Yoruba larin ara yin. Oburu Jojo. Ti e ba fe rere. Yoruba nation lawa nfe. A o se eru mo. Awon alale ngbo yin. Ese rere fun iran yin, Ki rere na le wa bayin ki eto fi Ile Bora.
Kodara to fun Awon Obawa lati maaso Ede Geesi ni Afin tiobajepe looto Oba Yoruba ni won tI kiibasepe asije eru biritiko,Ede Yoruba fun Oba Yoruba pelu ASA Yoruba ni Ile Yoruba fun Awa Iran Yoruba