Тёмный

ARA ILU PARIWO OLE LE OBA OLOTA LORI/GBOGBO ỌBA ILẸ̀ YORÙBÁ ORÍLẸ̀ ÈDÈ YORÙBÁ LÀ FẸ́ 22/10 /2024 

ÀṢÀKẸ́ TV SHOW
Подписаться 10 тыс.
Просмотров 7 тыс.
50% 1

Опубликовано:

 

23 окт 2024

Поделиться:

Ссылка:

Скачать:

Готовим ссылку...

Добавить в:

Мой плейлист
Посмотреть позже
Комментарии : 53   
@christianahogundele2427
@christianahogundele2427 День назад
Yoruba Nation no going back IJMN 🙏❤️
@AdesolaOladeji-d8m
@AdesolaOladeji-d8m День назад
Eku eto ma❤yoruba nation no going back🎉❤❤❤
@Sayitasebe
@Sayitasebe День назад
This must extend to others .O to gee
@JuliusJolaoso
@JuliusJolaoso День назад
Let the (Kings) Awon Oba put Ifa oracle down and ask what to do about Yoruba nation. Yoruba nation is the answer. They should not listen or bow for the Federal Republic of division.Mama Asake may God Almighty guide you and protect you and your entire family in Jesus Christ name.we love your program. God bless your heart. (AMEN)
@estheroluseun6188
@estheroluseun6188 День назад
More of the actions in Jesus mighty name Amen.
@estheroluseun6188
@estheroluseun6188 День назад
O ye ki won le loko ni o.
@fombookunowo5834
@fombookunowo5834 День назад
Free Yoruba Nation, Yoruba Nation No Going back
@seyioluwaseyin8323
@seyioluwaseyin8323 День назад
It's advisable that our obas respect the wishes of their subjects by sticking to what they want. If they work against the self determination of our Yoruba Nation, they stand the chance of regreting it.
@adelegiwa
@adelegiwa День назад
I need Yoruba nation now now.
@josephiwolode4876
@josephiwolode4876 День назад
Yoruba Nation no going back.
@elizabethsofela803
@elizabethsofela803 День назад
Yoruba Nation No going back
@williamsadesina3512
@williamsadesina3512 День назад
This caller said the truth.
@AdesIfemi
@AdesIfemi День назад
Orile ede Yoruba la fe ✊
@tinaparker5248
@tinaparker5248 День назад
The caller has said it all for me o 😢 all what he said is the absolute truth 😢 God Almighty bless him forever 🙏 ❤
@moreadeyemo1630
@moreadeyemo1630 День назад
Yoruba Nation now now
@OlajibutuEmmanuel-ty2er
@OlajibutuEmmanuel-ty2er День назад
Yoruba nation lafe
@estherfawibe1280
@estherfawibe1280 День назад
Orilede Yoruba lafe Ooooooo Yoruba nation no going back
@abosedeoluwatoyin6286
@abosedeoluwatoyin6286 День назад
Yoruba nation la feee oo Yoruba nation no going back
@abosedeoluwatoyin6286
@abosedeoluwatoyin6286 День назад
Oba ti di yepere haa o ga oo
@frankbolarinwa8062
@frankbolarinwa8062 День назад
Yoruba Nation is the only solution.
@OkeowoTaiwo
@OkeowoTaiwo 23 часа назад
Ile ife ni o ye ki ipade gbogbo lobaloba o ti waye.yoruba nation ni awa nfe o
@christianahogundele2427
@christianahogundele2427 День назад
Oonirisa loye kole ipade toripe oun ni olori awon Oba ile Yoruba emi gba awon Oba niyanju pe ki won mase jeki ipade na waye ni Odo oba elegusin tori onibode no ko see finu tan ore Fulani ni oo Sunday lgboho ko gbodo lo si ipade yen
@OyeledunOla
@OyeledunOla День назад
No retreat no surrender all we want is Yoruba nation nothing else that Yoruba nation
@JuliusJolaoso
@JuliusJolaoso День назад
Yoruba Nation is the way. No going back
@OyeledunOla
@OyeledunOla День назад
No matter Yoruba nation is the answer nothing else that Yoruba nation.
@julianafunke1708
@julianafunke1708 День назад
OLORUN a gbawa o
@OlawaleAkoidu-il7hn
@OlawaleAkoidu-il7hn День назад
huunmm inu agbole lati npari ija omo ile . inu Aafin ufe lo ye ki iru ipade yi ti waye . nitoripe nibe ni gbogbo ori Ade ti jade .BAB WA Ooni ibi gereje la nba Agba .
@josephiwolode4876
@josephiwolode4876 День назад
Itiju nla, oun to buru gbaa ni, oba te laarin ilu e.
@estheroluseun6188
@estheroluseun6188 День назад
Ode ete loku fun won. Olorun a da jo fun won. O ye ki won le loko ni.
@abosedeoluwatoyin6286
@abosedeoluwatoyin6286 День назад
Ori eja Titus ni
@olaiyapeter1043
@olaiyapeter1043 День назад
Gbogbo Eyin lọba l'ọba ilẹ yoruba, hàáà se bí awọn baba nla yín se lo igba níyì. Oga o, ẹti wa nfi ori adé wọ gbagede. Bàbá wa Ọọni Ile ifẹ olórí aládé gbogbo, Arole Oodua. Ìpàdé lọba l'ọba ilẹ yoruba hmmmm, ilẹ Oodua di ọwọ yin o. Baba wa arole Oodua, ẹse re kodara gbogbo ọmọ Yorùbá n'wo yin o. Eyiti wọn pawa ti to gẹ o.
@timothywale8055
@timothywale8055 День назад
Nipa ti ipade ti Tinubu fe ba awon oba ile Yoruba se, Tinubu kole pe awon Oba si ipade ti oma so esp rere fun Yoruba Nation, bikose fun atako fun Yoruba Nation, Pelu imo ti ara re nikan
@ajibolamuse2560
@ajibolamuse2560 День назад
Eku eto
@OyeyemiSalau
@OyeyemiSalau День назад
Eku eto Asake tv show Won sese bere ni Won si mase be fun seyi makide Ati awon Gomina toku Yoruba nation no going back
@OyeyemiSalau
@OyeyemiSalau День назад
Gbogbo awon oba nlo je poison ni agbara olorun
@AYEKOOTOTV812
@AYEKOOTOTV812 День назад
Yoruba nation la fẹ pelu ase Edumare
@atandajohn8176
@atandajohn8176 День назад
Fun gbogbo oba alade, ko tonaa fun awon oba yin fun ipade ti yio wa ye ni 7/11/2024. Nitori ile ife ni gbogbo yoruba ti se wa. Pls ojaja ooni tiwa, ile ife ni o ye fun ipade yi. Nitori oto ni ade isebaye otoni ade government, Ase be ni ile ife, gbogbo osa be ni ile ife. Ooni osa ema bawon lowo ninu awon odale. E mase ta Ase ile yoruba. Odua agbe wa.
@taiwotinuoye329
@taiwotinuoye329 12 часов назад
Yoruba Nation lafe. Freedom of Yoruba we need Yoruba freedom Yoruba freedom Yoruba Nation no going back
@taiwotinuoye329
@taiwotinuoye329 12 часов назад
All this Yoruba obas them useless them self because of money
@florencebeauty7322
@florencebeauty7322 День назад
Baba to soro lori oduduwa ko ye Kan so be,se awon wa laye nigba oduduwa ni,ati wipe ki won wa so ibi ti oduduwa ku si fun wa.niwongba ti won o ba le so ,kay ye pa itan ti won ma fi ma bu awa omo o tu a jire,asiko itan lori awon babanla wa ko niyi o Ire o.
@josephiwolode4876
@josephiwolode4876 День назад
Won tun npe l'oruko e.
@JuliusJolaoso
@JuliusJolaoso День назад
Eko ni Tinunbu ri emi okunkun meta sii Eko ni Agbara re wa.
@abosedeoluwatoyin6286
@abosedeoluwatoyin6286 День назад
Nkan ti fulani se nwo afin lo gbe won niyen
@ayoolababatunde4710
@ayoolababatunde4710 День назад
Eja oku Eko ni won n pe ni tejumalejo.
@user-sk4jf1mw4i
@user-sk4jf1mw4i День назад
You hasn’t mentioned of the bandits who are the killers both in there Farms
@DaramolaAdekunle-h3u
@DaramolaAdekunle-h3u День назад
E jeki a fi awon oba wonyi sile pelu iwa won. Lati ojo ti baba professor Banji Akintoye and chief Sunday Igboho pelu eyin Yoruba bloggers ati ajijagbara ti nsoro nipa OMINIRA YORUBA, awon oba melo ni o se atilehin fun yin. Nkan ti won ma je ko jeki won gbon. Nkan ti mo fe ki e mo ni wipe, millions awon oba kan ko le da ise Olorun lori Yoruba Nation duro rara. E tesiwaju ninu akitiyan yin lori oro Yoruba Nation, Olorun ko ni pada lehin yin titi eyin yio fi se aseyori.
@uklifetv1
@uklifetv1 День назад
Ejeka koju si awon oba ofo yi jo suru yi lomapawa ti ako ba soro
@AndrewToyinbo
@AndrewToyinbo День назад
Mama mi Asake, e ku ise takuntakun ti e nse yii o. I’m so sorry to disagree with the man that spoke so much as if he was there when Oduduwa lived. Awolowo committed suicide? Jakande revealed the plans? Now, can we ask this wise and knowledgeable man what has he done for the Yoruba people? About the killings, that it was the Hausa that were killing the people? Can he show any evidence? Can he show us one Hausa emir? How many Hausas are governors? Sir, we are not blind, we can distinguish the Fulanis from the Hausas. What solutions are you bringing to the table?
@olu7349
@olu7349 День назад
A thief is a thief.
@AdesIfemi
@AdesIfemi День назад
Beeni
@onanugaayomide2758
@onanugaayomide2758 День назад
Yoruba nation no going back.
Далее
News At 10 | 21/10/2024
45:13
Просмотров 27 тыс.
Меня знают уже все соседи😅
00:34
Fastest Build⚡ | Doge Gaming
00:27
Просмотров 1,1 млн
Nje Eranko ni nje Ooni? Esi oro Alfa
28:08
Просмотров 11 тыс.
THE BEGINNING OF YORUBA'S LIBERATION AND FREEDOM...!!!
1:03:49