Nigeria is dead. Divide Nigeria now to save life. God bless baba Akintoye. God bless Sunday igboho osha. God bless yoruba nation. Yoruba nation is the answer. Yoruba nation la fe
Yoruba Nation ni afe. Afe REGIONAL, CHIEF SUNDAY ADEYEMO KO BO LO SI IBI IPADE AWON OBA, TO BA LO PERIN GBAGBE YORUBA NATION. WON KAN MA PA OMO WA. TORI TINUBU TI SO TELE PE KI WON PA OMO WA CHIEF SUNDAY PE TI WON BA PA KONI JE KI OHUN DI PRESIDENT. GBOGBO EYIN WERE YORUBA TI ENSO PE EFE YORUBA NATION LAGBARA OLORUN TI RAN TIRAN YIN NI EMA SEGBE LASE EDUMARE AMIN
AWON OBA WONYI ELEBODE NI WON. AWON NI WON NDI WA L'OWO ATI KURO NI NIGERIA. O NPE KI EBI TO PA WON KU. O NPE KI AWON OBA TO SE AGBE. AWON NI OBA OLOSELU TI AWON POLITICIANS FI SI ORE OYE LAI SE IFA. OJU AWON OBA KO TI FO PELU EBI.