Тёмный
No video :(

Itan Lehin Iku Aare Afonja 13 

Itan Yoruba
Подписаться 26 тыс.
Просмотров 3,3 тыс.
50% 1

Apá kẹtàlá tí níbi àwọn Ọ̀yọ́ Mèsì ṣe gbabode fún Aláàfin Oluewu àti igbihin wọn pẹlu bí Aláàfin ṣe ló kí Emir Ilorin
Laji Abbas Whatsapp +2348023687432

Опубликовано:

 

26 авг 2024

Поделиться:

Ссылка:

Скачать:

Готовим ссылку...

Добавить в:

Мой плейлист
Посмотреть позже
Комментарии : 11   
@yusufsaheedadewale7751
@yusufsaheedadewale7751 4 года назад
Oluko agba, the best historian of our time
@Ayodeleist
@Ayodeleist 4 года назад
Ese o Oluko Agba. Olorun a gbo adura yin sir. E ku ise naa pelu.
@santamorestrengthinyourarm9412
@santamorestrengthinyourarm9412 4 года назад
Nibo ni IBARAPA ti sewa sir
@adeagboaremu1019
@adeagboaremu1019 4 года назад
A dupe lopolopo lowo yin fun ise ribiribi ti e n se lori Iran Yoruba. E seun o. Awon Yoruba bo, won ni; “ ina esisi kii jo ‘ni leemeji” sugbon awa Yoruba ko mu owe yi lo rara nitori ina esisi yi ti n jo iran Yoruba bo lati ojo pipe. Ina esisi yi kanna si n jo wa lowolowo bayi nitoripe a ri awon eniyan ti won n tako idasile Amotekun fun ile Yoruba ati ipolongo ipe fun idasile ori’le ede Ominira Oduduwa. Ina esisi ti koja igba egberun meji t’o ti n jo wa. A si pa owe lo jasi o fun awa ti a ni owe naa.
@thickbarbieskitchen1159
@thickbarbieskitchen1159 4 года назад
Eku ise oo
@wosilatamosu9017
@wosilatamosu9017 4 года назад
Laji Abbas Eku Ise opolo well ka kii gbogbo Awon ti se biribiri ni ti dada fun Yoruba Sugbon Tobe jubelo EMI tenu mo wipe Asiko ti to lati parapo jagun igbasile awa Yoruba sile Oba mi oke yio Bawa yanju ré ASE 🙏
@femipope18
@femipope18 4 года назад
Mo fe mo itan ijebu ode ati Ijebu ososa
@yusufsaheedadewale7751
@yusufsaheedadewale7751 4 года назад
Omo ososa ni emi na
@yusufsaheedadewale7751
@yusufsaheedadewale7751 4 года назад
Omo osanlobirinpo ni emi
@olajideisola8594
@olajideisola8594 4 года назад
E se pupo oluko agba, pelu gbogbo ogun ni le yoruba se Aresa ati Olugbon ko kopa kankan no?
@crownedking2567
@crownedking2567 4 года назад
Gbogbo oro won yi jeki mo pe Oogun "Medicine" ko ran Ogun "war". Olootu Abbas,ki lo de ti Alaafin Oyo o se kansi awon ti Ondo ati Ekiti parapo pelu awon Ijebu fun iranlowo lati bori emir Ilorin?
Далее
Itan Lehin Iku Aare Afonja 14
48:32
Просмотров 3,4 тыс.
Lehin Iku Aare Afonja 15
1:09:51
Просмотров 3,7 тыс.
Cute kitty gadgets 💛
00:24
Просмотров 12 млн
AKUDAYA LO ILE IWE
11:33
Просмотров 16 тыс.
Itan Lehin Iku Aare Afonja 11
54:55
Просмотров 3,6 тыс.
A tour to Aleshinloye Palace , Ibadan
20:13
Просмотров 10 тыс.
Itan Lehin Iku Aare Afonja 8
1:05:38
Просмотров 3,9 тыс.
Itan Eko Ninu Itan Afonja
1:29:33
Просмотров 4,5 тыс.
Itan Lehin Iku Aare Afonja 1
1:02:41
Просмотров 6 тыс.
ITAN OGUN OTEFON 4
1:02:55
Просмотров 6 тыс.