To be sincere those guys are funny, Olootu Olorun aama fun yin she o, Olorun yio bukun yin ati awon amugbalegbe yin na, Ejowo ejeki olofofo o ki awa ololufe yin ninu eto ton bo, afe gbo ohun re, God bless you sir, ha moti so oyinbo! 😁😁😁😁😁😁
This was the sweetest episode so far! It love the way EYA refilled their accounts at the end! But it was the two comedians blessings that melted my heart! Brilliant all the way around!
Ẹ kú ìṣe takuntakun E jọ̀wọ́ mo ní lọ ìwé òwe tàbí ìwé ìtàn dowe Yoruba Tí ẹ bá lè tó mi sónà bí mo ṣe lè rí wọn rà inú mi máa dùn gan-an ni Ẹsẹ púpò Èmi ni tiyín ni tòótọ́ Alàgbà Awolumate Olamide Julius Láti ipinle Kwara