Oyamilenu wipe ako mo baba OBASANJO yi si nkan ti odara ni ile Yoruba. Kofe ki enikeni ju Oun lo amo Olorun Oba nwo gbogbo Eyin eniyan buruku ni ile Yoruba.
Obasanjo tells traditional rulership to adhere to rule of law as treading path of unlawful judiciary Governor of states should be given their accolades by traditional rulers God bless Obasanjo
Kii sejo agbalagba Omo ale yen. Ti won ba ti na owo agbara si to ti bere si ni gbo bi aja, tabi to bere si ni po eje lenu ni, ko ni bere si ni ma leri pe inkan ti oun se ko buru. It is not too late. His action is a dishonour to Yoruba tradition and all Yorubas. They must teach him a lesson so that others would learn.
Only Yoruba nation is the answer to all this... Because if Yoruba nation come to reality, Yoruba oba's will surely regain their respect back from politicians🤷 but without Yoruba nation,we YORUBAS WILL SURELY CONTINUE HAVING POLITICAL KING'S IN OUR PALACE🤦♀️🤔ALALE YORUBA E DIDE,NITORI ASA ATI ISESE YORUBA TI FE MA PARUN OOOO🙄ALALE YORUBA,E DIDE KIO TO PE JU BAYI LO HMMM...
It's about time he becomes severely irrelevant in the affairs of Nigeria at this point in time. He has never been in support of any Yoruba Nation agenda.
Omo Ale Yoruba ni Obasanjo. Ohun lo ko gbogbo dukia awon Yoruba fun awon Fulani ati Ibo. O tun so Lagos Airport di Muritala Airport; WNBC di NTA ati be be lo. Omo Ale ti o wa da Ile ru! Awon Onile yo yanju re, laipe. Ase n'tedumare!
O si so fun wa iye ibo ti tinubu ati awon alatako re ni, ti o fi mo pe ko wole, nigba to je pe iwo lo ka ibo, iwo na si ni INEC ti ofin fun lagbara lati so eni to wole. Omo ale jatijati.