❤. Ko Si Eni Ti O Le Fi Owo Bo Ogo Osupa, Ogo Orun, Ogo Akoko. Ogo Irawo, Ogo Ojo To Npa Eru Pa Omo, Ton Npa Ika ati Olododo. Ogo Re Ko Ñi Se Fowo Bo. Onilara Ko Ni To E. Won Ko Ni Gbayi. Iku Ti Won Ro Si O, Ni Yio Pa Won. Loruko Jesu Kristi.
Adetinubu omo president Olori Bouda Adisa Iya ijo ti o ni certificate Ijoba Ajadematonile Adunbarinmatoshi mama stop sebe iyawo Honourable president new Asiwaju bloggers Abo Olorun a daju lori yin tomotomo ,tokotoko lagbara Olorun Oba