Тёмный

TANGIIRI YORUBA TRADITIONAL MOVIE GABRIEL AFOLAYAN|| MOJI AFOLAYAN|FEMI ADEBAYO|PEJU OGUNMOLA. 

Ojopagogo TV
Подписаться 39 тыс.
Просмотров 50 тыс.
50% 1

A woman gave birth to 9 children to 9 different fathers, did things go well with her, and what is the end of her life, the husbands and the children...PEJUOGUNMOLA, RAZAQ OLAYIWOLA, Ojopagogo) ADEBAYO SALAMI,.KAREEM ADEPOJU Baba Wande) TUNRAYO ADEOYE, MUYIWA ADEMOLA, MOJI AFOLAYAN OLAYIWOLA, FEMI ADEBAYO, FATHIA BALOGUN, GABRIEL AFOLAYAN, DAYO AMUSA, SODIQ ADEBAYO, AFIS ENIOLA, EZEKIEL ATILOLA, RUKAYAT SOLIU,OLANIYI AFONJA (Sanyeri) TIJANI ADEKOLA(Compo) BOSE AKINOLA, AYANFE ADEKUNLE (Monsuru) WALE AKOREDE (Okunu) OKIKI ADESHINA OSHIN (Janmole) VICTORIA AJIBOLA (Ajijagbara) AYO OLABIYI (Bobo B)

Развлечения

Опубликовано:

 

8 янв 2018

Поделиться:

Ссылка:

Скачать:

Готовим ссылку...

Добавить в:

Мой плейлист
Посмотреть позже
Комментарии : 24   
@yusuffomolara6691
@yusuffomolara6691 6 лет назад
Hmmm yoruba movies ti dorikodo kini di. Ibo ni awon ijinle yoruba yii Wa ati awon Agba osere yii Wa ooooo Baba wande Baba ti oro Won ma n pawa leerin. Very soon now to me I will stop to watching yoruba movies bcos there is no lesson in yoruba movies again. Bcos I like my language yoruba yoruba I can never 4geting home ojopagogo welldone sir dat is why i like u 👍❤
@salauddinabdulhafeez7204
@salauddinabdulhafeez7204 Месяц назад
@julietbello6590
@julietbello6590 3 года назад
This move is really interesting and educating, well done guys 😊
@tayetaiwo5382
@tayetaiwo5382 Год назад
This is good job, kudos to the writer and all the actors and actress. More wisdom to you guys IJN
@haleemahyusuff7936
@haleemahyusuff7936 4 года назад
Hmmmm Enibimo omo nio sin enitio bi gan won ni so oku e fun aja, kosi ountio leere ibiyemi jeere agbeere. Meemah OSF
@ajoseadewunmi5042
@ajoseadewunmi5042 3 месяца назад
To say I knew when this movie came out then,but am just seeing it
@turkiano1621
@turkiano1621 4 года назад
I never regret watching this movie 🎥, OSF
@user-fd3fv3ce8v
@user-fd3fv3ce8v 3 месяца назад
Wow so interesting
@mixedcouples
@mixedcouples 5 лет назад
Wow wonderful movie
@janetcharles6559
@janetcharles6559 3 месяца назад
Very interesting, well done ✅
@abdulrasheedrukayat7447
@abdulrasheedrukayat7447 2 года назад
This is educative. Kudus to all the crew. Thanks so much
@tinaparker5248
@tinaparker5248 Год назад
Very interesting movie 🎥🍿🍷🌹👍🤝
@saheedadekunlesunmonu1084
@saheedadekunlesunmonu1084 2 года назад
Gabriel afolayan,well done
@viconos6363
@viconos6363 Год назад
Very interesting and Educative 💯
@mariamlawal7662
@mariamlawal7662 5 лет назад
Thanks for uploading this wonderful movie
@aishatlasisi6884
@aishatlasisi6884 6 лет назад
Hmmm! Very lnteresting and educative movie
@olamyalade2695
@olamyalade2695 6 лет назад
Wonderful movie and good actors
@aderinokunsegun8263
@aderinokunsegun8263 4 года назад
Nice movie
@aderinokunsegun8263
@aderinokunsegun8263 4 года назад
OSF
@obeyadesoji8430
@obeyadesoji8430 6 лет назад
Mo kí yín Alàgbà Olayiwola Rasaki Ojopagogo fún ìṣe ńlá yí. Laakaye yín ó ní jooba láéláé lágbára Olódùmarè a àṣẹ. ÌKÒKÒ omi ọgbọ́n Imọ àti òye yín elegbara ayé ó ní fo lórúkọ Jésù Kristi àmín. Mo ní àwọn ìbéèrè méjì sí mẹta. 1. Kin ni wọn máa ń fi Adìẹ Irana ṣe leyin ti wọn ba ti gbé òkú de ìtẹ́ tán, ṣe jíjẹ ni àbí wọn yóò pá sì orí saare òkú??? 2. Ǹjẹ́ o yẹ kii Obìnrin máa bímọ sì ilé ọkọ méjì sí mẹta, gẹgẹ bí Iyawa Ibiyemi ṣe see nínú sinnimo Tagiri??? 3. Ǹjẹ́ bí igbẹyin àwọn Obìnrin tí ó bá bímọ sílè ọkọ méjì sí mẹta gbogbo ṣe máa ń rí ní igbẹyin Ibiyemi ṣe rí yí nínú sinnimo Tagiri yí??? Ẹ jọ̀wọ́ mo fẹ́ ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè mi yí, yóò dára fún yín, ilé isẹ yín ó ní jóná, Olúwa kò ní fí èyí ṣe òpin fún ilé isẹ yín lórúkọ Jésù Kristi Olúwa wa àmín.
@OjopagogoTV
@OjopagogoTV 6 лет назад
Obey Adesoji ,e seun alagba, Idahun si ibeere yin akoko, won ma n pa adie irana yi, nigba ti won ba gbe oku de ite, eje adie yi ni won a ro si ara igi ti won ma fi n bo oku mo koto ki won to da erupe boo, jije si ni adie yi fun gbogbo eni ti o ba ni ife si lati je. Owe kan fidi e mule pe won ma n je e ni "ADIE IRANA KII SOHUN A JE GBE " idahun si ibeere keji Ko ye. Idahun si ibeere keta, kii se bee o, ohun to koju senikan eyin lo ko selomii, iriri ati ona ti kaluku gba fi sile oko ka yato sira won, oun lo si le toka si irepo ti yo wa laarin awon omo ti o ba bi kiri, gbogbo won ko ni igbeyin won le ri bi tibiyemi. E seun a dupe o, e ku ife, Olorun a ma bu kun ile ati ona yin ati gbogbo eni to n darapo mo ikanni yi. E SEE PUPO.
@odunifao2764
@odunifao2764 6 лет назад
hmmm
@akinloyeblessingsubuola9717
@akinloyeblessingsubuola9717 3 года назад
Just watching this❤️
@arikkyheritagetv6373
@arikkyheritagetv6373 4 года назад
Wow nice One, so interesting, Secam OSF
Далее
ТРОЛЛИНГ СКАМЕРА СТАНДОФФ 2
00:59
YÉÈPÀ - Full Comedy filmed Play by Tunde KELANI
2:19:19
Ayan Agalu
1:30:30
Просмотров 30 тыс.
ASHIRI OLOGBO Yoruba Movie
1:32:34
Просмотров 26 тыс.
IGBA ORO - Yoruba Movie
1:58:36
Просмотров 213 тыс.
OWO EJE
1:59:05
Просмотров 857 тыс.
🍁 Экскурсия года
0:19
Просмотров 1,8 млн
ЧУТЬ НЕ УТОНУЛ #shorts
0:27
Просмотров 9 млн