Kabisanra, o se o ku ise, o ku atun se, may Allah continue to protect, preserve and provide for you. You will not be tired by the special grace of Allah.
What is causing dealay for court judgement on this issue of immamship of Ogbomosho land, I think the court should give it's final judgement so that all these mess Will end, may Allah SWT saves the situation
Sebi dáadáa ni o n ṣe; o need lati pariwo tabi sunkún now; ogun ni i sini mu, èpè ki í sini jà. So gbogbo Alfa Ogbomoso ni é sọ di elebo nitori wipe wọn ni ki é ma jẹ ogun Olohun. No problem ALLAHU will pay everybody and everyone for his actions at the due time. Boya ni o mo wipe ọmuti ni é ni ti o ni awọn Alfa ba ayé oun jẹ ati iya ti baba tiẹ gangan kọ sí iya rẹ lọwọ. Ogbomoso gba Tolia pelu ọkan kan latari wipe won ro wipe olódodo ni; nigbati wọn wa ri í wipe alaburu ni, é bẹrẹ were lori wipe ko kuro n'ibi ti o fi eru gba. É o ni ri eleyii muje, ti é ba ti ṣe iru é ti é muje ri.