Se aburo e kole wole fun yin kuro ni sitting room...this is plan work o....o mo nkan to se mo ...sugbon o ranti pe emeji ni😂😂😂 otun pe aburo ko basun... elo si ewon ni taaraaa
Ohun ti owa ni okan awon mejeji ni won nse o, oro oti ko rara, nigbati oba ti awon omo olomo je tan owa nbebe. Ki ise ejo won ejo awon omo olori buruku yen ni, baba won ati iya won ni awon mererin fijo, isekuse tiwa ninu eje awon idile wonyen tipe tipe.
Parents have a huge role in the life of the children . You will notice these evil brothers have been involved series of scandals that’s above their age ..
Orisirisi awon omobinrin buruku yi na po ni igboro, awon ni won bi awon omo ale jo si ile Yoruba, iru awon omo tiwon bi ni won ya ajinigbe, agbebon, agbe sunmonmin, ati awon were ni arin igboro loni.
Ki lode ti e bu obinrin, Se okunrin kan ko lo basu to fi bi omo yan, omo to ba da ti baba ni eyi ti oba kun die Kato fun iya le ma da le lori, a fi Kolorun ko obinrin yo lowo yin.
Ema binu simi ma iwa alainitiju ti omobinrin yen hu ni omun inu bimi, emi feran lati mon ebi tabi ikan ninu awon obi obinrin ki ato dijo ma rin po, nitori wipe omo buruku se'fe anon buruku ni ko dara. Ki omobinrin losi ile okunrin ni igba akoko ki okunrin ri ihoho re, ohun ti oburu ni ma. Eniti ko mon ebi re kankan, ha oga o.
Ejowo ebami ra ( another Red Belt ) fun arakunrin yi ati aburo re, leyin igbati won ba mun tan, ki adajo bami fun enikookan won ni ewon ogota odun, ki won sare lo ki won bo pa. Won ( plan ) fun omo yen ni, kosi awa wi, won ti nse tipe tipe, eleyi koni akoko
Osejepe ogun state ni inkan buruku ti n ma sele ni gbogbo igba? 🤔 we all knw that in yoruba land nah ogun state ritualist full and many other things like this, se ogun state nikan Lowa nile yoruba ni?😢 why tie se ya alaburu eda bayii?
All lies........ Both brothers are rapist i want to first believe him that his brother's is innocent until he mention Kaosara, definitely they both always plan and chop same girls that's unfair 💔put him to jail where he will no longer see bullet again talkless of sleeping with innocent girls........